Home / Art / Àṣà Oòduà / Ebuka Obi-Uchenda àti ìyàwó rè, Cynthia Obianodo níbi ayeye ìgbéyàwó alárédè ti Banky W àti Adesua Etomi.

Ebuka Obi-Uchenda àti ìyàwó rè, Cynthia Obianodo níbi ayeye ìgbéyàwó alárédè ti Banky W àti Adesua Etomi.

     Ojó tí a ti n retí ti pé o! Ebuka pín àwòrán aso tí wò lo sí #BAAD2017 tí ó túmò sí Banky Adesua 2017. Níbi tí ó ti fi ara rè hàn. E wo bí gbajúgbajà yí se ya àwòrán ara rè àti ìyàwó rè níbi ìgbéyàwó pèlú abó oúnje tí won je.

Send Money To Nigeria Free

About Awoyemi Bamimore

x

Check Also

Ọdún orò gbìnà yá, ìdájí ní àwọn olórò yóò fi máa yíde ìlú níṣẹ̀yin

Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe aifẹsọ kebosi,lai rẹni jo o,ati pe n ta o ba fẹ o bajẹ,o ni bi o ṣe yẹ ka ṣe e,eyi lo bi atunse abẹnu lati fopin sawuye wuye to waye latari aawọ to suyọ laarin awọn onisese ati awọn ẹlẹsin meji ti o ku(Kitẹẹni ati Musulumi).Wayi o, igbakeji alaga fun ẹgbẹ agbaagba nilu Isẹyin, Alhaji Bọlaji Kareem, ti kede pe ija ti dopin, ogun si ti tan lori aawọ ọrọ sise nilu Isẹyin.Kareem, ẹni to soju ...