Home / Art / Àṣà Yorùbá / Gómìnà Yahaya Bello ri èro amúnáwà (Transformer) gégé bí isé rè àkókò ní ìpínlè Kogi. 
transifoma

Gómìnà Yahaya Bello ri èro amúnáwà (Transformer) gégé bí isé rè àkókò ní ìpínlè Kogi. 

Gégé bí ìròyìn se so, Gómìnà ìpínlè Kogi: Yahaya Bello ri èro amúnáwà tí agbára rè tó Egbèédógún (300KVA) ní òpópónà kan ní Lokoja gégé bí isé rè àkókó léyìn tí ó ti lo odún kan àti ààbò lórí ipò.

Ìkan lára ò n lò èro ayélujàra (facebook) tí ó pin àwòrán náà, ó Ko síbè pé : ó lo pèlú okò tí ó tó ogún tí gbogbo rè férè jé SUV láti lo sí isé takuntakun tí ó se yí. Tí ó bá jé pé pípè padà wá Asòfin Dino Melaye yorí sí rere ni èyí ni kò bá jé isé àseyanjú rè kejì. Mo gbósùbà fún Gómìnà Bello !

Asòfin Dino melaye náà pín àwòrán yí tí ó so pé : àríyá ńlá bí Yahaya Bello se sí isé rè ààkókó láti ìgbà tí ó ti di gómìnà èro amúnáwà kan ní Koto pèlú Kápètì pupa. O so pé Allah ya isa kai!!!!!!!

Continue bellow for the English translation

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

Enter Captcha Here : *

Reload Image

x

Check Also

Àwòrán ìsìnkú Tagbo Umueke ní ìpínlè Anambra .

      Òré Davido, tí ó n jé Tagbo Ifeatuchukwu Umueike ni ó sùn re ní ogún’jó osù kèwá odún, 2017 (20/10/2017) ní ìlú tí a bi sí. Ní ìjoba ìbílè Osumenyi ní ìpínlè Anambra .    Àwon òré àti aféniféni ni won péjú p’ésè níbè láti fun ní ìbòwò ìkeyìn tí ó jé wípé àwon olùdábòbò sì n se ìwádìí ikú tí ó pa á….