Home / Art / Àṣà Yorùbá / Iwure Owuro: 14-05-2016

Iwure Owuro: 14-05-2016

E MAA WI TELE MI :
…..
*Fitila ogo mi ko ni ku.
*Aso iponju ko ni se dede orun mi.
*Oluwa ba mi segun ota ile.
*Edumare ba mi segun ota ode.
*Ina omo ko ni jo mi.
*Ina Aya/Oko ko ni jo mi.
*Oluwa mu mi tayo laarin akegbe e mi(Ase).

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

Ti o ba ka iwe yii fi ara e han