Home / Art / Àṣà Oòduà / Seyi Makinde di gómìnà kẹ́ta tó kó àrùn Covid-19
Seyi Makinde

Seyi Makinde di gómìnà kẹ́ta tó kó àrùn Covid-19

Oni ogbon ojo, osu keta ni ayewo gomina ipinle Oyo, Alagba Seyi Makinde jade, ti ayewo naa si gbee pe o ni arun naa. Oun ni o maa je eleeketa gomina ni orileede yii ti ayewo fihan pe won ni arun kokoro naa.


Gomina ipinle Bauchi, Bala Mohammmed ni o koko ni, ki ayewo to gbe ti gomina ipinle Kaduna , Nazir El-Rufai jade. Eyi lo mu ki gbogbo eka ijoba maa pariwo ki onile ko gbele nitori ajakale arun naa.

Arun naa ko mo olowo, bee ni ko mo talaka. Arun naa ko ni aponle fon egbe oselu to n se ijoba lowo de bi to maa ni fun egbe oselu ti ko se ijoba rara. Bi ojo ni arun naa se n rin, “eni ti eji re ri ni eji n pa”.

Seyi Makinde di gómìnà kẹ́ta tó kó àrùn Covid-19
Ìròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí

Send Money To Nigeria Free

About ayangalu

x

Check Also

President Muhammadu Buhari

Ìṣẹ parí fún òṣìṣẹ́ tó bá gbé àṣírí Ìjọba jáde lọ́nà àìtọ́—Ìjọba àpapọ̀

Ìṣẹ parí fún òṣìṣẹ́ tó bá gbé àṣírí Ìjọba jáde lọ́nà àìtọ́—Ìjọba àpapọ̀ Ṣé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, ìlú tí kò sófin, ẹ̀sẹ̀ kò sí níbẹ̀, gẹ́lẹ́ bẹ́ẹ̀ ni ọ̀rọ̀ Orílẹ̀ yìí dà báyìí, bí Ìjọba àpapọ̀ se ni ìwé ìdádúró ni òun yóò fún ẹnikẹ́ni tí aje ìwà ìbàjẹ́ gbígbé ìwé àti àṣírí ìjọba síta lórí ayélujára lọ́nà àìtọ́ bá sí mọ́ lórí. Ó ní ìwé ìjọba kan tó fara hàn lórí ayélujára láìpẹ́ yìí níbi tí o ...