Home / 2017 / November (page 9)

Monthly Archives: November 2017

“Mo máa já we kulè ” Wizkid kìlò fún obìnrin tí ó ní ìfé rè .

     Òkan lára àwon Olólùfé obìnrin tí ó ti nífèé Wizkid ti pin sí orí èro ayárabíàsá (Twitter) láti fi èhónu rè hàn wípé òun nífèé Wizkid sùgbón ó so wípé ànfààní nlá ni kí Wizkid fé òun kí ...

Read More »

Arábìnrin yí ni ó ya àwòrán tí ó ti fi èro ìbánisòrò rè hàn tí ó sì gbàgbé wípé òrá ìdáàbòbò (condom) tí won ti lò wà ní àrin esè rè.

    Arábìnrin yí ni ó ti fún àwon èèyàn ní òrò so léyìn tí ó fi èro ìbánisòrò rè tí ó jé aláwò pupa hàn nínú ilé ìtura tí ó wà làímò wípé òrá ìdáàbòbò èyí tí won ti ...

Read More »

Emma Nyra dùn nínú aso ìwè tí ó wò ní Dubai .

    Olórin orílè èdè Nàíjíríà, Emma Nyra ti gbìmò láti fi èbùn tí olórun fun han gbogbo àgbáyé lórí èro ayélujára ( Instagram). Olórin tí ó n lo ìsinmi rè lówó ní Dubai ti pín àwòrán tí ó yà ...

Read More »
cross talk

CrossTalk BULLHORNS: FAKE DIPLOMACY

Read More »
usa

Transracial Weirdo Claims He’s a Filipino Woman

Read More »
Hezbollah leader

SouthFront Documentary about Hezbollah (MUST SEE!)

Read More »
yemni

Yemen – Appeal to President Putin

by Peter Koenig Dear President Putin, Yemen, a peaceful and extremely poor country is being slaughtered, literally slaughtered by the Saudis, with the full weapons, funding and political support of the United States of America and the UK. The rest of ...

Read More »

Peter okoye se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún mérìndínlógójì pèlú Omotola, Ebí àti òré.

    Peter Okoye tí ìnagije rè n jé Mr. P ti lé odún kan ní àná ó sì se ayeye ojó ìbí náà pèlú àwon ebí àti òré ní ilé rè. Gbajúgbajà òsèré, Omotola náà wà níbè.

Read More »

Omobìnrin tí kò ti dàgbà púpò ni àwon olùdábòbò yin ìbon pa ní Agbonchia , ní ìpínlè Anambra .

    Gégé bí èni tí ó pin sí orí èro ayélujára (Facebook) focuselema, àwon agbófinró ti jèbi pípa omobìnrin yí (tí àwon míràn ní okúnrin ni ) ti kú sí Agbonchia . A kò mo ohun tí ó fa ...

Read More »

Kenneth Okonkwo àti omo rè yo ní àrà òtò.

Bí eni tí ó pin se so wípé . “Àwon òbí ní láti sóra fún àwon nkan tí won bá n se n’íwájú àwon omodé nítorí won n wò wá”.

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb