Home / Art / Àṣà Oòduà / Ere Opolo: Matimatiisi to gbona felifeli

Ere Opolo: Matimatiisi to gbona felifeli

Ile itaja kan n ta masiini okada ati keke maruwa. Apapo gbogbo oja ti won ni je. meje (apapo okada ati keke maruwa), gbogbo oja won lapapo si ni taya mokandinlogun.

Nje o le so iye okada ati keke maruwa to wa ninu soobu naa, to ba je wi pe taya meji ni okada ni ti keke maruwa si ni meta?

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

general

Army General Expose the Foreign Missions Behind Boko Haram And Bandits In Nigeria