Home / Art / Àṣà Oòduà / Ile Igbimo Asofin ipinle Kwara ti kede ojo ayewo awon komisanna tuntun
Kwara

Ile Igbimo Asofin ipinle Kwara ti kede ojo ayewo awon komisanna tuntun

Orisun

Ile Igbimo Asofin ipinle Kwara ti kede ojo ayewo awon komisanna tuntun
Olayemi Olatilewa

Ile igbimo asofin Ipinle Kwara ti kede ogunjo osu kewaa odun yii [20/10/15]gege bi ojo ti won yoo se agbeyewo awon komisanna tuntun ti gomina fi ranse.

Awon oruko ti gomina ipinle Kwara, Abdulfatah Ahmed fi ranse ni yii: Engr. Musa Yeketi, Engr. Idris Garbage, Otunba Taiwo Joseph, Aro Yahya, Barrister Abdurazak Shehu Akorede ati Bolakale Mayo.

Awon yoku ni Barrister Kamaldeen Ajibade, Engr. Demola Banu, Alhaja Fumilayo Oniwa Isiaka ati Mahmud Babatunde Ajeigbe.

Bakan naa, olori ile igbimo asofin ipinle naa ni awon ti se ifilole igbimo alabe sekele eleyii ti Hassan Oyeleke n dari lati jiroro pelu awon komisanna naa saaju ojo ayewo won.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

saraki

Ìdíle Saraki àti ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara dájọ́ ìpàdé

Lẹ́yìn tí Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara ti tẹ̀lé òfin tí wọ́n wo ohun ìní ìdílé Saraki èyí tí wọ́n ń pé ibẹ̀ ni Ilé Arúgbó ní ìlú Ilorin, ìpínlẹ̀ Kwara, gbogbo àwọn tọ́rọ̀ kan nínú rẹ̀ ti wá gbà láti yanjú aáwọ̀ láì ti ọwọ́ Ilé ẹjọ́ bọ̀ ọ́ mọ́.