Home / Art / Àṣà Oòduà / Olúbámbí, also hailed as Àfọ̀njá, Ewélérè King of Koso

Olúbámbí, also hailed as Àfọ̀njá, Ewélérè King of Koso

Olúbámbí, Àfọ̀njá, Ewélérè
Ọba a Kòso
Àtijẹ, àtimu, ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀
Ẹ mọ́ safẹfẹ yẹ̀yẹ̀ sí wa mọ́
Afẹfẹ yẹ̀yẹ̀
Ewé ọdán ṣe jù bẹ́ẹ̀ lọ
Ẹran ló fi jẹ
Afẹfẹ yẹ̀yẹ̀

Olúbámbí, also hailed as Àfọ̀njá, Ewélérè
King of Koso
To eat and to drink, are separate matters
Stop your vanity ways with us
Vanity, sheer vanity
The ọdán leaf tried vanity with us
And a goat ate it up.
Vanity, sheer vanity.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb