Home / Art / Àṣà Oòduà / Osise Arik Airline Ba Naija Loju Je Niluu London: Won Ka “Lafun Funfun Alata’ Mo o Lowo

Osise Arik Airline Ba Naija Loju Je Niluu London: Won Ka “Lafun Funfun Alata’ Mo o Lowo


Owo ti te CHIKA EGWU UDENSI, okan ninu awon osise ile ise oko ofurufu ARIK Airline ni papako ofurufu HEATHROW ti ilu London pelu ogun oloro kokeeni.

Ogun oloro ti won ka mo bobo naa lowo ni won ni iye owo re yoo to nnkan bi ogorun milionu owo naira.

Oruko Nigeria ti emi n gbiyanju lati tun se ni awon kan si n gbinyaju lati maa yimo inu erofo loju awon ebo.

Laaarin emi ati CHIKA EGWU UDENSI ija sese bere ni o.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

general

Army General Expose the Foreign Missions Behind Boko Haram And Bandits In Nigeria