Lati inu iwe Iroyin Owuro to jade lose to koja ni iroyin naa ti jade wi pe Ajimobi ati Amosun ti pada ninu ileri eto eko ofe ti won se ileri re fun awon ara ilu. Won ni ki olomu da omu iya re gbe; won ni ki awon obi maa san owo idanwo asejade (WAEC) awon omo won funra won.
Ki ni ero awon eniyan nipa igbese tuntun yii? E le ka awon ero ara ilu ninu linki isale yii.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


