Laipe yii ni Feyikemi Niyi-Olayinka, okan ninu awon sorosoro ori telifisan, dagbere irin-ajo re siluu London. Aworan re ni yii pelu okan lara awon osere tiata Nollywood, Sola Sobowale, niluu London. Lara awon fiimu olokiki ti Sola Sobowale se ni fiimu Lagidigba, Ilubirin (ilu awon obirin). Nigba ti OLEKU to je fiimu ti Feyikemi kopa gege bi Asake ko le pare ninu itan,
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

