Home / Art / Àṣà Oòduà / Àwọ̀ ni Édè Yorùbá – Colours in Yoruba Language
Àwọ̀ ni Édè Yorùbá

Àwọ̀ ni Édè Yorùbá – Colours in Yoruba Language

DúdúBlack
Àwọ̀ Ojú Ọ̀runBlue
Àwọ̀ igiBrown
Àwọ̀ EérúGray
Àwọ̀ EwéGreen
Àwọ̀ ÒféfèéOrange
PupaRed
FunfunWhite
Pupa rusurusuYellow
Àwọ̀ dúdúDark color
Light colorÀwọ̀ tí ó mọ́lẹ̀
ColorsÀwọn àwọ̀
 Ojú Ọ̀run dúdú díẹ̀The sky is blue
Ológbò rẹ funfunYour cat is white
 Àwọ̀ dúdú ní ó yàn láàyòBlack is his favorite color
Àwọ̀ pupa kì íṣe èyí tí ó yàn láàyòRed is not his favorite color
Ó nwà ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ aláwọ̀ rẹ́sùrẹ́súShe drives a yellow car
 Mo ní irun dúdúI have black hair

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

iwure tooni

#Iwure Owuro Tooni lati enu Kolawole Ifarotimi

Iba Olodumare. Iba Akoda Aye, Iba Aseda Aye, Iba Eniyan. Ekaro, eku ojumon. Ojumon ire gbogbo. Loni, Olodumare yoo silekun gbogbo ire fun o yoo si ti ilekun ibanuje, ekun, ipayin keke pa. Lori jije ati mimun re loni, ooni gbe omi p’ari, oosi niigbe ata pari gbona orun lo pelu. Ina ola re konii joku rebete. Ooni fo loju, ooni ro lapa ro lese. Gbogbo ire ti o ti wo agbole re, koni pada baje. Ooni fi eda re ...