@DeleMomodu, okan ninu awon oga oniroyin ile Naijeria, eni ti pupo ninu awon akegbe re feran lati maa pe ni Bob Dee, ni okan ninu oju meji re n yo lenu bayii.
Won ti se ise abe fun adari ati alakoso magasininni Ovation to kari aye, ise abe naa si kesejari.
Adura wa ni wi pe ki Oba oke tun bo fun okunrin naa ni alaafia to peye si i. Amin
E wo adura awon eniyan ti won fe Dele Momodu nibi:
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

