Fun awon ti ko mo, Dele Momodu ni oniroyin akoko to koko se afihan foto Diezani Alison-Madueke. Eleyii to ya nigba to se abewo si minisita fun epo robi nigba kan ri ni ilu London.Oga Dele Momodu ti pada se afihan Madueke leekansii. Ekunrere iroyin nipa obirin naa kosi ni pe jade ninu iwe iroyin re.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more


