Leyin gbogbo rukerudo oselu to ti n sele nipinle Kogi, eleyii to bere leyin iku Abubakar Audu, awon egbe APC ti yan Yahaya Bello gege bi eni ti yoo ropo Audu to ku. Ogbeni James Faleke naa si ni won fe lo gege bi igbakeji re. Sugbon titi di akoko yii, a ko le ti so boya Faleke faramo aba lati di igbakeji okunrin naa.
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

