E MAA WI TELE MI :
……
*Sekere kii rode ibanuje, oro ibanuje koni je temi.
*Tijo-tayo ni ti sekere, oro ayo ati idunnu ko ni tan ninu ile mi.
*Ogun idile ko ni bori mi.
*Ki osu yii to pari, maa gbe ohun rere se
*Oluwa gbami lowo ogun alaroka.
*Aso ogo mi koni ya mo mi lorun.
*Ijade ati iwole mi ko ni ja siku.
*Eni eleni koni k’ere ise mi(Ase).
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

