Home / Art / Àṣà Oòduà / Lobatan: Won ti n ge tomato lori foonu chinco

Lobatan: Won ti n ge tomato lori foonu chinco

Awon Yoruba ni ti ogun eni ba daniloju, eniyan fi i gbari ni. Ile ise China kan ti n se foonu, OUKITEL, ti kede wi pe, eni ba foju ana wo eegun, ebora nii boru won laso.  Won ni to ba je ti ojulowo foonu to je wi pe konfaamu ni, won ni foonu tuntun ti awon sese se ti n je OUKITEL U7 gan-an lodu to jawo. Koda, won ni nibi ti foonu naa da won loju de, eniyan le ge tomato, alubosa, ata, ila, efo lori re. #Lobatan

 

Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti