Home / Art / Àṣà Oòduà / Olojo Ibi

Olojo Ibi

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa TUNRAYO IBRAHIM ti won je okan pataki ninu ebi Oodua Rere.
Iyalode olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu alafia ara ati ibale okan. Ni oruko Oluwa e o ni ba won na oja warawara nile aye beeni e o si ni dagba yeye, gbogbo ohun rere ti n mu’le aye rorun fun eda ni Eledua yoo fi jinki yin. E o gbo, e o to, e o fewu pari, e o ferigi jobi, e o gbele aye sohun rere bi o ti wa wu ki e pe to laye e o ni f’oju mo saare omo lase Edumare.
Kabiyesi ati awon Oloye ati gbogbo ebi Omo Yoruba Atata pata nileloko nki yin wipe IGBA ODUN, ODUN KAN NI O….

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Aláàfin Ọ̀yọ́ Has Been Crowned With Ade Ṣàngó

KABIYESI IKU BABA YEYE ALAAFIN ỌBA ABIMBỌLA OWOADE COMPLETED TRADITIONAL RITES AND EARNED HIS RESPECTIFÁ chose our ALAAFIN for us and now you can see he is following the tradition of his ancestors. If you do not know how powerful Alaafin is, check the crown on his head. This crown is believed to be very powerful. Ade Ṣàngó.This powerful crown must be given to Alaafin by Baba Mọ́gbà Sàngó who would place it on his head after completing the orò ...