Home / Art / Àṣà Oòduà / Òrékùnrin Àtijó Vera Sidika Fi Ìhòhò Rè Hàn Látàrí Pé Ó Fi Sílè Bá Olówó Kan Ní Nàìjíríà Lo. 
vera

Òrékùnrin Àtijó Vera Sidika Fi Ìhòhò Rè Hàn Látàrí Pé Ó Fi Sílè Bá Olówó Kan Ní Nàìjíríà Lo. 

Léyìn wíwá ènìyàn pàtàkì ní ìlú Kenya ,Vera Sidika pín àwòrán tí ó fi hàn wípé kò bá ti tún gbàgbé odómokùnrin míràn ní orílè èdè Nàìjíríà tí owó kún àpò rè. òrékùnrin àtijó rè dapadà fún un nípa pínpín àwòrán ìhòhò rè . Èyí se àfihàn. okùnrin kan náà tí Sidika lo gbogbo àkókò rè pèlú, tí ó ma gbe e lo sí ile ìtajà tí ó gbajúmò kan ní Dubai. Tí ó sì wa okò bògìnì pèlú.
 Gégé bí kiss se so, ó pín àwòrán igbáyà tàbí esè omú ènìyàn pàtàkì Kenya tí orí rè sì hàn. Ohun tí ó jé kí á rí àrídájú wípé òun ni. Tàtúù tí ó wà lára Vera ni ó tì wá láti gbàgbó wípé ìhòhò náà ti rè ní…

Continue after the page break for English version

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti