Gbajúgbajà òsèré Tonto Dikeh àti Asàkóso ìwí àti Àsà (minister of information and culture) Muhammed Lai. Ya àwòrán nínu okò ojú òfurunfú nínu ipò tí ó wà ní ìsàlè. “mo wo bí ayò mi se kún tó nígba tí Hon. Muhammed Lai sòrò kárakára nípa ìpìlè mi. Bí ènìyàn bá gbájú mó isé rè tí ó se olórun a ma fi èrè si. Inú mi ń dùn fún ìgbésè tuntun…..
English Version
Continue after the page break
Pages: 1 2