Home / Art / Àṣà Oòduà / E wo ohun ti won fi ibeji da lara

E wo ohun ti won fi ibeji da lara


Nje e le biliifu eleyii?

Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa.

Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won.

Awon ore iyawo meji to tele won, ibeji ni won.

Awon omo iyawo obirin, ibeji ni won. Awon omo iyawo okunrin, ibeji ni awon naa.

Ilu India ni igbeyawo naa ti waye.

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti