Home / Art / Àṣà Oòduà / Ajimobi ati Amosun Da Ara Ilu: Won Ni Ko Si Eko Ofe Mo
ajimobi

Ajimobi ati Amosun Da Ara Ilu: Won Ni Ko Si Eko Ofe Mo


Lati inu iwe Iroyin Owuro to jade lose to koja ni iroyin naa ti jade wi pe Ajimobi ati Amosun ti pada ninu ileri eto eko ofe ti won se ileri re fun awon ara ilu. Won ni ki olomu da omu iya re gbe; won ni ki awon obi maa san owo idanwo asejade (WAEC) awon omo won funra won.

Ki ni ero awon eniyan nipa igbese tuntun yii? E le ka awon ero ara ilu ninu linki isale yii.

Orisun

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti