Toke Makinwa sèsè dé sí orílè èdè South Africa láìpé yí gégé bí ó se ń rìn káàkiri àgbáyé láti di gbajúgbajà ònkòwé. Ìmúra rè yanilénu nígbà tí ó wo aso aláwò pupa férééfé (pink Gert Johan) àti bàtà tí a mò sí Calvin Klein isé owó Harvellastyles ni, ó wà lójú ònà tí ó ńlo sí TouchHD fún ìfi-òrò-wá ni -lénu -wò lórí redio. Nígbà tí ó jáde pèlú oba ilé-isé redio Tbo Touch.
Toke ti wà ní ìpele tí ó kéyìn ní ìrìnàjò àgbáyé látàrí dídi ògbó-n-tarìgì ònkòwé tí ó ń tèlé àwon ìpele tó tó ní United State, Ghana àti United Kingdom.
Yó ò gba tí to wó bo ìwé àti kíka ìwé ní ojó Àbáméta…..