Home / Art / Àṣà Oòduà / Ayo Ab’ara Bintin !

Ayo Ab’ara Bintin !

Ope ni fun Olorun nitori ti o seun ti anu Re duro laelae. Mo layo lati so fun yin wipe Eledua fi Omo Tuntun Jojolo da ebi kan pataki ninu ilu yi lola. Tii se ebi Alhaja wa Adetunji Adenike J ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Oodua Rere.

A wa ngba ni adura wipe, a ti mo ibere omo yi, a o ni mo opin re lase Edumare. Aisan ti n se iya omo leyin ibi omo ko ya nile lodo yin ni oruko Oluwa. Gbogbo ohun ti e nilo lati fi to omo yi ti yoo fi je eniyan laye ni Eledua yoo fi s’eke yin.

Ki Olodumare wa wo ola omo tuntun jojolo yi, gbogbo eda ti nwoju Oluwa fun ohun ayo bayi ki oba mi oke wa dawon lohun ni kia lase Edumare.

~Abel Simeon Oluwafemi

About ayangalu

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti