Home / Art / Àṣà Oòduà / Kíní orúkọ tí wọn npè Ìsọ yìí ní èdè ìlú ti’yin?
oja

Kíní orúkọ tí wọn npè Ìsọ yìí ní èdè ìlú ti’yin?

Aku ataro óò Adé kú ọjọ yìí Kíní orúkọ tí wọn npè Ìsọ yìí ní èdè ìlú ti’yin náà?????? #iya lájé

About ayangalu

5 comments

  1. Ayòolá wonlèwonlè

    Ìsọ̀ lékulẹ́ja tàbí Ìṣòro eléwé ọmọ.

  2. Zosa

    Iso alagbo, elewe tabi leku leja

VI

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

amoke

Itan Omooba Amoke

Omooba obinrin kan gbe ni ilu alayo, orewa pupo ju oruko re si nje Amoke ni ile Yoruba atijo. Orewa pupo debi pe gbogbo okunrin ilualayo niwon ko enu ife si, koda awon okunrin ilu agbegbe won gan o gbeyin. Amoke n ma bu gbogbo awon okunrin ti oba soro ife leti re koda atun pariwo lewon lori. Oro yin kan Oba ilu ti oje baba re lomi nu. Loru ojo kan, Oba ji Amoke sile o de ba so ...