Awon Yoruba ni ti ogun eni ba daniloju, eniyan fi i gbari ni. Ile ise China kan ti n se foonu, OUKITEL, ti kede wi pe, eni ba foju ana wo eegun, ebora nii boru won laso. Won ni to ba je ti ojulowo foonu to je wi pe konfaamu ni, won ni foonu tuntun ti awon sese se ti n je OUKITEL U7 gan-an lodu to jawo. Koda, won ni nibi ti foonu naa da won loju de, eniyan le ge tomato, alubosa, ata, ila, efo lori re. #Lobatan
Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more

