1.Tooro toki Adifafun Alamala ketu,ekun ire lo n sun won ni ebo ni ko se,iya o si baba o si tooro toki ope gbigba ni o gba mi tooro toki.
2. Ewe le ole le alele le wure adifafun Orunmila baba o ma se owo imele,imele ni mo se ti mo fi lowo,laya,bimo nire gbogbo ero yaa e wa wo ise imele n se.
Tagged with: Otura alaketu
amadorogbeche@gmail.com