Home / Art / Àṣà Oòduà / Yanju Adegboyega: Ohun ti won wi ti ko koreeti”

Yanju Adegboyega: Ohun ti won wi ti ko koreeti”

“Nje e mo pe “oye to kan ara Iwo, o n bo wa kan ara Ede, tawon kan maa n wi yen ko koreeti?

Ilu kan n be ni ka to de Ede ti won n pe “Awo”, ilu yii ni ibujokoo ijoba ibile Egbedore nipinle Osun.

Oye to kan ara “Awo” n bo wa kan ara “Ede” ni won n wi”. – Yanju Adegboyega

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb
x

Check Also

Free Dele Farotimi | Seun Kuti