Home / Art / IFA ANATOMY: Etí/ Ear

IFA ANATOMY: Etí/ Ear

Etí. Ear, also fringe, edge, border, perimeter.

Ó pawo lékèé
Ó pÈṣù lólè
Ó wá kọtí ọ̀gbọin sẹ́bọ

Etí odò yato sétí aṣọ.
Ọ̀rọ̀ tí a bá fẹ́ kí aditi gbọ́
Etí ọmọ rẹ̀ là á ti í sọ o.

S/he called Awo a liar
S/he called Esu a thief
And turned a deaf ear to the call for sacrifice.

The ear of the river differs from the ear of the cloth
Whatever you want to tell a deaf fellow
Say it to the ear of his/her child.

~Moyo Okediji

About admin

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb