Oju ni mo ro.Ara ilagbede.Omo aworin-tunrin-ro.Ba a ki won nire.Won ki i je.Omo owu ni won fi n je ni.Ojo obe ire ba di meji.Lo dowon-gogo.a ki i bimo nire.Ko pose owo.Eru onire ni i robe ide.Awon iwofa ibe a ro baba.Omo bibi onire ni i remu sekele.Omo rowo-rowo-rowo.Balagbede o ba rowo.Toloko taladaa.Won a maa so lona oko.Ki lo mu ki won maa so lona oko?Eyin omo yoruba e dahun ibeere mi oke yi
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more



A dúpẹ́ púpọ̀ fun oríkì orílẹ̀ Ìrèmògún yìí. Ṣùgbọn kò rọrùn púpọ̀ láti kà nítorí àìní ̀àmìn ohùn lókè àti nísàlẹ̀. Ẹ jọ̀wọ́ é bá wa se àtúnkọ rẹ̀.