Olayemi, odun to n bo yii, odun emi ati iwo ni. Eyin e fota sile ki won ma gbogun. E fika eniyan sile ki won ma soogun. Mo tile tun gbo wi pe awon kan tun lo n bogun onire. ...
Read More »
admin Comments Off on Ikini odun lati owo Olayemi Olatilewa Oniroyin Agbaye
Olayemi, odun to n bo yii, odun emi ati iwo ni. Eyin e fota sile ki won ma gbogun. E fika eniyan sile ki won ma soogun. Mo tile tun gbo wi pe awon kan tun lo n bogun onire. ...
Read More »admin Comments Off on IROYIN OWURO ose yii ti jade ooo
Iru iku wo lo pa Sikiru Ayinde Barry Wonder? Inu iwe Iroyin Owuro ose yii ni e o ti ri. E gbiyanju ke e bere lowo fendo yin. Ogorun naira pere ni.
Read More »admin Comments Off on Photo of the day: (Future omo Awo)
There are awos and there are ogberis, but the young man chose to be the former! The beautiful omo Awo doing his thing. The future of Ifa. Ifa a gbe yio se. Àṣẹ o See the full picture when you continue ...
Read More »admin Comments Off on Yinka Ayefele sodun fun awon alaini ati omowewe
Aimoye awon omo wewe ni won pejo si bi ayeye odun keresimesi ati babakeresi ti ile ise redio Fesh FM ti Yinka Ayefele eleyii to waye ni Music House, ile orin Ayefele, to kale siluu Ibadan. Asekagba naa lo waye ...
Read More »Okan pataki ninu awon oloye egbe APC nipinle Ondo, Niran Sule-Akinsuyi, ti so yanya wi pe niseju Gomina Olusegun Mimiko ni egbe oselu PDP ipinle naa yoo fi di ohun a-fi-seyin teegun fiso. Oro yii lo n so nigba to ...
Read More »admin Comments Off on Faleke n mura ija nipinle Kogi *Omo oloogbe Abubakar Audu n be leyin re.
*Omo oloogbe Abubakar Audu n be leyin re. *Kilode ti Tinubu ko da soro naa? Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Lojo Aje to koja yii ni rugudu ti n lo lagbo oselu nipinle Kogi tun bureke si i nigba ti Ogbeni ...
Read More »Alaga egbe oselu APC, oloye John Odigie-Oyegun ti fi da awon omo Naijiria loju wi pe, kosi ipadaseyin ninu yiyo owo iranwo ori epo robi. Oyegun lo n soro yii nigba ti n gbalejo awon iko kan lati inu egbe ...
Read More »admin Comments Off on Aregbesola ya ₦130m lati ko ile iwe girama kan
Iroyin Lati Ọwọ Olayemi Olatilewa Gomina Rauf Aregbesola tipinle Osun ti lo si ileewe girama, Olufi Middle School to kale si Gbongan ni Ijoba Ibile Ayedaade to wa nipinle naa. Nibi ayeye ti won ti n si ileewe naa ni ...
Read More »admin Comments Off on “Ajo NFF kii ta agbaboolu soke okun” Aare NFF
Ogbeni Amaju Pinnick to je aare ajo ti n risi ere boolu alafesegba, Nigeria Football Federation, ti fesi lati tako awon aheso kan ti n lo nigboro wi pe, ajo NFF n se bisineesi tita agbaboolu soke okun. O ni ...
Read More »admin Comments Off on Esun idigunjale la o fi kan eni to ba gbegidina ti n gbowo odun” Olopaa Ipinle Ogun
Komisanna awon olopaa ipinle Ogun, Ogbeni Abdulmajid Ali ti kede wi pe,ile ise olopaa ipinle Ogun ti wa ni imurasile lati gbogun ti iwa idaran to seese ko suyo lasiko poposinsin odun taa wa yii. Ninu oro Ogbeni Abdulmajid, eleyii ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more