Home / Author Archives: ayangalu (page 169)

Author Archives: ayangalu

iwure

E Ase iwure yi ooo

Huunn Mose kabiyesi fun oba mi. Oba ajidara Oba toje dada owo e lowo. Iyi ti o da no nbe lowo eledumare Mo wa nbe o. Eledumare Jo o ma fiwa dara buruku o. Ma fun wa ni.omo abami eda. Oooo ...

Read More »
buhari leave

Ebami Dasi Oroyii, aare orile ede Naijiria yii Muhamedu buhari…

eku ojumo gbogbo awa omo yoruba rere asikoyi atuwa lara ooooo Ase, ebami dasi oroyii, aare orile ede naijiria yii muhammedu buhari ti yowo yose kuro lori oro epo, epo tiwa di N145 per littre, sugbon eje karantipe nigbati ijoba ana ...

Read More »
Gbolun kan

Gbolun kan fun baba oni bata yi

Eku dede asiko yi ooooo. E jo eyin omo ilu mi

Read More »
oruko

Oruko Kan Fun Iya omode yii ?

Eyin Eniyan mi Eje Kia Rerin die. Oruko kan fun iya omode yii ?

Read More »
tomatoes

Oro ton’lo Lowo bayi: E wo tomato timo ra ni 500 naira

Eku Dede asiko yio eyin eniyan Atata tin GBE inu ilu Yoruba Atata, oro tonlo Lowo bayi ni mo muwa oro elo obe to won gogo yi ma ni mofe kia soro Lorie o. E wo tomato timo ra ni ...

Read More »

Ibeere Toni: 15.05.2016

Nje Iwo leso “FACEBOOK PASSWORD” re fun Ololufere????? Huuum ema paro ooo

Read More »
arewa toni

Arewa Asa Toni: Afeez ati Mide Martinez Abiodun

Ko so’ogun mo bee si ni ko so’ote mo ni igbeyawo eleyi ti o ku die ko dojubole. Oserekunrin Afeez Abiodun “Afeez Owo” ati iyawo re Oserebinrin Mide Martin ni ti mu ife won padabo sipo. Laipe yi ni edeaiyede ...

Read More »

Iwure Owuro: 14-05-2016

E MAA WI TELE MI : ….. *Fitila ogo mi ko ni ku. *Aso iponju ko ni se dede orun mi. *Oluwa ba mi segun ota ile. *Edumare ba mi segun ota ode. *Ina omo ko ni jo mi. *Ina ...

Read More »
Invasion 1897-

Epic Nollywood Movie: Invasion 1897 – Full Movie HD – By Lancelot Imasuen

A young Edo professional finds himself in hot water after attempting to recover stolen artifacts from a British museum. Based on the true story of the fall of the Benin Empire, this truth continues to reverberate through the Ifa Community ...

Read More »
ifa

Aku ojumo lokun !

Lobinrin wa se dada laji bii.. Adupe lowo OLODUMARE too mu emi ati iwo losii ipo oku lati ano too tun jiwa pada saiye, si aye rere nitori gbogbo eni bati sun ti oku ope ni fun ODUMARE.. Moo wa ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb