Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa MONSURAT KEHINDE ADENEKAN ALANI ti won je okan pataki ninu ebi Omo Oodua Rere. Maami olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se ...
Read More »Eto Olobe Loloko Sokoyokoto Toni
Olorun ogo ni fun oruko re, oba to ni kokoro Iku ati iye lowo, oba ti o le pa, oba ti o le ji, adupe lowo eledua, oba ti o fi aanu re pawa mo. “FURAIDI IRESI” (fried rice) ni ...
Read More »Odo Iwoyi – E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo wa pata lokunrin ati lobinrin, lomode ati lagba wipe a ku ise oni, a si ku abo sori eto wa eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. E wa nkan fidile tabi ki e gbiyanju fidile ...
Read More »Arun Karun Konifile Awa Se Ibugbe o
Eyin tiaa..akuu gbalegbata oni o…arun karun konifile awa se ibugbe o. Ase..Paronure lawaa..Se e gbagbe pe lati onilo di ola.faaji nson. Leyin Elere ti okan yin yan laayo. Pe kowa kolu siwa nibadi. Emaa gbagbe pe.idalu niselu. Onje tin lo ...
Read More »Idile Alayo: E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo
Mo ki gbogbo wa pata lokunrin ati lobinrin, lomode ati lagba wipe a ku ise oni, a si ku abo sori eto wa eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. E wa nkan fidile tabi ki e gbiyanju fidile ...
Read More »Eeto Owe L’esin Oro
YAKUB BUKKY – Nje a tun ti de loni gegebi ise wa ni gbogbo ojoru. Oro enikokan wa koni dojuru oo (amin), a ki gbogbo kaabo si akootun eeto yin, eeto wa owe l’esin oro, oro l’esin owe, ti oro ...
Read More »Iwure Owuro Toni 04-05-2016
E MAA WI TELE MI : ……… *Owo ko ni ri mi sa. *Oju owo ko ni pon mi. *Ojo ibukun mi ko ni di ojo abuku. *Alaaanu mi ko ni ko’yin si mi. *Edumare ma je ki n teni ...
Read More »Iwure Osu Tuntun 01-05-2016
E MAA WI TELE MI : ……… *Osu karun-un yii, osu ire owo ni fun mi. *Osu ire ile kiko ni fun mi. *Osu ti maa ra oko ayokele. *Osu igbega lenu ise mi ni. *Osu idunnu ni yoo je ...
Read More »Happy New Month To You All
|| | | || || || || | Good morning my people, hope your night was great, I wish you all happy sunday and new month. This month will be a blessed and prosperous one for us amen. The corpus ...
Read More »ÒRÚNMÌLÀ BARAGBOMÌRÈGÚN, AWÍMOLÓGBÓN ( the great teacher that fortifies one with knowledge)….
Have you ever wonder WHY HUMANS SHOUT AT EACH OTHER IN ANGER ??? Òrúnmìlà has the answer to that in the holy Odù ÒDÍ-ÌWÒRÌ (ÌDIN MÀLÙKÓ……very interesting…. Òrúnmìlà was, in company of his students (Amósùn & Amórè)going to the river ...
Read More »