?
Read More »Opele ide (brass divination chain)
Opele ide (brass divination chain)
Read More »Ti o ba ni #500, osi fe da ina okele, Bawo Ni wa Sena ?
TI O BA NI #500 KOSI KEROSINE KOSI GARRI TABI ELUBO OSI FE DA INA OKELE BAWO NI WA SE NA #500 fi se okele #antyfolashadealawada
Read More »Iwure Owuro 21/03/2016
E MAA WI TELE MI : …….. *Aye ko ni gbe ounje mi fun aja je. *Atije-atimu mi ko ni nira. *Oluwa so egan mi dogo. *Aye ko ni ta epo s’aso ala mi. *Fitila ogo mi ko ni ku. ...
Read More »Ewi Toni – 20.03.2016
Ojumo ti mo Eda ti ji saye Eda ti ko mose asela Ka ji ni kutu hai Ka gbegba pota Iya Akanke nko O ti re werenjeje Baba Talabi da O ti sare re kutuwenji Ki ni n le wa? ...
Read More »Ile ati Oko oju Omi Yi wa Fun Tita
ILE= 7.6MILLION NAIRA OKO OJU OMI= FREE OMI=FREE EMA NA NI INA KUNA OOOO Elo le fe san??? #antyfolashadealawada
Read More »Why must Spiritualist suffer when they have the power to end suffering ?
“SPIRITUALISTS have everything in abundance but yet they are not the richest; They have the supernatural powers to manifest the impossible but yet they are the most simplest; Their metaphysical dominion over all existing beings makes them Supreme in all ...
Read More »Oro Sunuku – Ore Mi, Iran Kefa .
.( Ni gbongan adulawo ni Yunifasiti Afonja, awon eniyan n wole leni tere, eji tere. Won n gba tikeeti, won si n wole jokoo. Awon ti o fe safihan sinima naa n gunke, won nso. Won nfa waya, won gbaradi. ...
Read More »Iwure Owuro – 14.03.2016
*Edumare ma fi omo pa mi lekun. *Oluwa ma fi mi pa omo mi lekun. *Ile alayo mi ko ni di ile ibanuje *Ogun aye ko ni bori mi. *Iji aye ko ni ja lu mi. *Ayo mi ko ni ...
Read More »Iwa Dabi Eyin
Toju iwa re iwo ore mi. Maa ranti wipe iwa-lewa. Ewa bii iwa ko si. Bi o ba dara bii egbin. Ti o tun rewa bi okin. Eran ikan ni lojo tiku ba de. Sugbon iwa lohun ti kii ku. ...
Read More »