Home / Author Archives: ayangalu (page 34)

Author Archives: ayangalu

ìrun Asham

Àwọn aláṣẹ orílẹ̀-èdè Saudi Arabia ti fòfin de kíkí ìrun Asham ní àwọn mọ́sálásí tó wà níbẹ̀

Àwọn aláṣẹ Saudi sọ pé kò ní ín sí ìrun Asham tàbí Taraweeh, ní àwọn mọ́sálásí tó wà ní ìlú Makkah àti Medina, àyàfi tí àrùn apinni léèmí coronavirus bá ti káṣẹ̀ nílẹ̀. Mínísita fún ọ̀rọ̀ ẹ̀sìn lórílẹ̀-èdè náà, Abdullateef ...

Read More »
Yahaya Bello

Èmi kò ní àrùn coronavirus – Yahaya Bello

Gomina ipinle Kogi,Ogbeni Yahaya Bollo lo n forere lori ero ayelujara pe ki won se fi orokoro ko oun lorun, oun lo ni arun covid-19 gege bi awon oloselu Kan se n gbee kiri. O ni loooto ni adari aabo ...

Read More »
Akoko Technical University

Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ Oyo

Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ OyoÌròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí Akoko Technical University to fi ikale si ilu Ibadan se bebe ni irole ana. Won pese aso ibomu ara otun fun ijoba ipinle Oyo. ...

Read More »
ifa books

Ifa books at affordable prices (now in stock)

ifa books

Read More »

In Loving Memory Of Prof. Akinwunmi Ishola

Professor Akinwunmi Isola was a Nigerian playwright, actor, dramatist, culture activist and scholar. He is known for his writing in and his work in promoting the Yoruba language. Books: Efúnṣetán Aníwúra, Iyálóde Ìbàdàn, and Tinúubú, Ìyálóde Ẹgbá, Madam Tinubu, MORE Prof. ...

Read More »
ofun meji

Happy Ose Ifa to all Ifa devotees globally.

Happy Ose Ifa. An Odu references all situations, circumstances, actions and consequences in life, based on the innumerable ese (poetic tutorials/recitations) relative to the 256 Odu coding. In other words an Odu is your life path. Each Odu has over ...

Read More »

Ìjìyà ‘Frog Jump’ ni ọlọpàá India fi jẹ àwọn tí kò bọwọ fún òfin kónílé-o-gbélé

Ìjìyà ‘Frog Jump’ ni ọlọpàá India fi jẹ àwọn tí kò bọwọ fún òfin kónílé-o-gbélé Fẹ́mi Akínṣọlá Oríṣìríṣi ìjìyà ni ìjọba orílẹ̀-èdè India ti gbà nípaṣẹ̀ àwọn agbófinró láti máa jẹ àwọn kọ̀lọ̀rànsí tí kò bọ̀wọ̀ fún òfin kónílé-ó-gbélé ní ...

Read More »
buhari

Àdúrà làsìkò yí gbà pẹ̀lú ìfaradà láti ṣẹ́gun àrùn apinni léèmí Coronavirus–Ààrẹ Buhari

Ààrẹ Buhari kí àwọn ọmọ Nàìjíríà kú àfaradà bí gbogbo nǹkan ṣe ń lọ lásìkò Coronavirus yìí Nínú ọ̀rọ̀ ìkínni kú ọdún Àjíǹde tó fi ṣọwọ́ sáwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ààrẹ Buhari ṣàlàyé pé ìgbáyégbádùn àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kìí ...

Read More »

Àwọn dókítà ilẹ̀ China tó wá sí Nàìjíríà kò ní tọ́jú aláìsàn kankan’

Àwọn Dókítà láti ilẹ̀ China tó ṣẹ̀sẹ̀ dé sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nítorí àjàkálẹ̀ àrùn Coronavirus kò ní tọ́jú aláìsàn kankan. Iléeṣẹ́ láti ilẹ̀ China to tó ṣe ojú ọ̀nà àti ojú irin( CCECC Nigeria), ló fi àtẹjáde náà léde pé ...

Read More »
lai

Ìjo̩ba máa gbé pé̩ré̩gi kaná pè̩lú àwo̩n oníròyìn ìdàlúrú – Lai Mohammed

Minisita fun eto iroyin ati asa ni orileede yii, Alhaji Lai Mohammed ni ijoba apapo ko ni gba ki awon kan fi iroyin aboosi da ilu ru. O ni “oloju ko ni laju re sile ki talubo woo”. O ni ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb