Ọrọ̀ kò tíì tán lórí àwọn Olóyè mọ́kànlélógún tí Ilé ẹjọ́ sọ pé kí wọ́n lọ rọọ́kún nílé nílùú Ìbàdàn. Kọmíṣọ́nnà ètò ìdájọ́ tẹ́lẹ̀rí nípìńlẹ̀ Oyo, Ọ̀gbẹ́ni Michael Lànà ló ṣe ìkìlọ̀ fún wọn pé, kí wọ́n yé pe ara ...
Read More »Àmọ̀tẹ́kùn: Ẹ̀ṣọ́ ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) ‘Àmọ̀tẹ́kùn’ ṣetán láti bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ káàkiri ilẹ̀ káàárọ̀ o ò jíire
Ọ̀rọ̀ ti di olójú ò níí yajú ẹ̀ sílẹ̀ kí tàlùbọ̀ ó yíwọ̀ọ́ àti pé ọmọ onílùú kò níí fẹ́ ó tú lọ̀rọ̀ dà báyìí ó, bí.
Read More »Naira Marley ń rìn ní bèbè ẹ̀wọ̀n lọ́dún 2020 bí kò bá fara hàn lórí ẹ̀sùn ìjọ́kọ̀gbé – Ilé ẹjọ́
Naira Marley ń rìn ní bèbè ẹ̀wọ̀n lọ́dún 2020 bí kò bá fara hàn lórí ẹ̀sùn ìjọ́kọ̀gbé…..Ilé ẹjọ́ Àdúrà ká má rẹ́jọ́ loníkálukú ń gbà,kí èṣù ó sì má yá wa lò.Ṣùgbọ́n bí nǹkan ṣe ń lọ yìí fún Naira ...
Read More »Ohun t’ọ́kùnrin ń ṣe l’Ekiti, obìnrin lè ṣe é. Àjọ̀dún Àṣà ìbílẹ̀ lékìtì
Àṣà àti ìṣe wà nínú n tíí ṣàfíhàn èèyàn bí ọmọ ọkọ tàbí ọmọ ìdàkejì n ló díá fún bí onírúurú ohun tẹ́ ẹ̀ tilẹ̀ mọ pé ó wà láyé yìí se dohun àfojúrí níbi ayẹyẹ àjọ̀dún àṣà ọdún yìí ní ipinlẹ Èkìtì, .
Read More »Mu pàrágá wakọ̀ l’Ọyọ, kóo kó sí páńpé̩ ìjọba
Omi tuntun ti rú, ẹja tuntun ti wọ ọ ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́. Awakọ̀ mẹẹdọgbọn ni ọwọ́ òfin ti tẹ̀ nìpínlẹ̀ náà lórí ẹ̀sùn pé wọ́n ń mutÍ nígbà tí wọ́n tún ń wa ọkọ̀.
Read More »Odù kan gorí àtẹ,Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 goróyè Àràbà nílẹ̀ẹ̀bàdàn
Odù kan gorí àtẹ,Ọdẹ́gbèmí Ọdẹ́gbolá11 goróyè Àràbà nílẹ̀ẹ̀bàdàn Fẹ́mi Akínṣọlá Erin wo! Àràbà Awo ilẹ̀ Ìbàdàn, Ògbó Awo Oyewusi Amọo Fakayode wọ káàl’ẹ̀ sùn.Ọjọ́ a kú là á dère,èèyàn ò sunwọ̀n láàyè. Bí àlá ló ń ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹni ...
Read More »Ìjọ Ọ̀rúnmìlà Ifákáyéjọ afi òtítọ́ ayé hàn
Àwa ni ìmọ́lẹ̀ fún gbogbo Ìjọ mímọ́ Ọ̀rúnmìlà ní gbogbo àgbáyé nítorí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tí àńpè ní Ifá ni a fín to Ìjọ tiwa Ifá(ọ̀rọ̀ Ọlọ́run)ni afi kó ayé jọỌ̀rúnmìlà(aṣíwájú rere)ní abá ni táyése Ẹ wá bá ọ̀rọ̀ ẹnu Ọlọ́run ...
Read More »Òlódumarè les bendiga, que tengan una feliz y bendecida tarde.
Ẹ̀là mo yìn bọrú.Ẹ̀là mo yìn bọyè.Ẹ̀là mo yìn bọ’ṣíṣẹ. Òlódumarè les bendiga, que tengan una feliz y bendecida tarde. Ijuba. Doy reverencia. Ìdà kí si ònà ní nse ejó lè yínA’dífá’fún Esin ohun AgboTi wòn nse Awo losí ilé ...
Read More »Ó dèèwo̩ f’ó̩kùnrin lati gun kè̩ké̩ e̩lé̩se̩ mè̩ta pè̩lú obìnrin – Gaduje
Ó dèèwo̩ f’ó̩kùnrin lati gun kè̩ké̩ e̩lé̩se̩ mè̩ta pè̩lú obìnrin – GadujeGomina ipinle Kano, Alhaji Umar Gaduje lo soo dofin nibi idanilekoo awon Musulumi kan to waye ni ipinle naa. O ni lati odun 2020 to n bo, okunrin kankan ...
Read More »Ààrẹ Buhari ní ààbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan
Ààrẹ Buhari ní ààbò wà fún ẹ̀mí ààrẹ́ àná, Goodluck Jonathan Ààrẹ Buhari ti pe Ààrẹ àná, Goodluck Jonathan lórí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀,láti báa kẹ́dùn lórí ìkọlù àwọn agbébọn tó wáyé ní Òtuòkè tíí ṣe ìlú abínibí rẹ̀ nípìńlẹ̀ Bayelsa. Nínú ...
Read More »