Ní ìsàlè yìí ni àwòrán sineto Obanikoro àti sineto Oluremi Tinubu àti àwon tó kùn. Ní ìpàdé kejilélógún (22nd) ní ibi ìpàdé àwon sinetò ní agbègbè èkó …. English Version after the page break
Read More »Inú àwon olólùfé 2baba dùn púpò nígbà tí won rí olólùfé won ní Glomega music tour tí ó wáyé ní Victoria Island, ní ìlú èkó.
Gbajúgbajà olórin 2baba jé òkan lára àwon tí ó korin ní Glomega tour ní VI ní ìlú èkó. Ó tún wú àwon ònwòran lórí nígbà tí ó f’akoyo lórí ìtàgé. Ewo àwòrán bí ó se Ń dá won lárayá n’ísàlè.. ...
Read More »Àwon olólùfé Biodun Okeowo wí fun pé kí ó pa àwòrán rè tí ó wo aso tí ó fun ré.
Òsèré Biodun Okeowo tí a mò sí Omobutty, ni àwon olólùfé rè ń sòrò sí látàrí àwòrán tí ó pín ní bi tí ó ti wo aso tí ó gbé èyà ara rè jáde… Continue after the page break for ...
Read More »Akékòó Odún Keta (300l) Ti Oau Ti Eka Èkó ‘Pharmacy’ Rì Sómi, Tí Ó Sì Kú Sí Odò-ìwè (Swimming Pool) Ní Hòtéèlì.
Akékòó odún keta (300l) ti eka èkó pharmacy, Obafemi Awolowo University; pàdánù èmí rè Lánàá léyìn ìgbà tí ó rì sómi nínú odò-ìwè (swimming pool) ní hòtéèlì tí a mò sí Hilton. A mò ó sí Fatile Emmanuel. Ìsèlè yí ...
Read More »Ìkan Lára Àwon Ìyá Ń Dá Gbé (Single Mum) Orílè Èdè Nàìjíríà Múra Bíi Okùnrin Láti Se Ayeye Àjòdún Baba (Father’s Day).
Ò n lo èro ayélujàra (facebook user) Ebere Amalaha tí ó ń jé ìyá ń dá gbé, múra bíi okùnrin láti se ayeye àjòdún baba tí ó wáyé ní ojó kejìdínlógún osù kefà (June 18). Pín àwòrán ara rè bí ...
Read More »Òrékùnrin Àtijó Vera Sidika Fi Ìhòhò Rè Hàn Látàrí Pé Ó Fi Sílè Bá Olówó Kan Ní Nàìjíríà Lo.
Léyìn wíwá ènìyàn pàtàkì ní ìlú Kenya ,Vera Sidika pín àwòrán tí ó fi hàn wípé kò bá ti tún gbàgbé odómokùnrin míràn ní orílè èdè Nàìjíríà tí owó kún àpò rè. òrékùnrin àtijó rè dapadà fún un nípa pínpín ...
Read More »Owó Sìkún Àwon Olóòpá Te Arákùnrin Tí Ó Máa Ń Jí Okò Gbé Ní Yenegoa.
Nígbà tí won ti mu fún èsùn kan náà. Arákùnrin tí ó wà nínú àwòrán ní ìsàlè yìí tí ó yan isé okò jíjígbé láàyò ni owó sìkún àwon olóòpá bà ní Yenegoa, ní ìjoba ìpínlè Bayelsa fún ìgbà keta. ...
Read More »Oko Mi Máa Ń Fowósí Fóòmú Rè Wípé Òun Kò Tí Ní Ìyàwó ,erànmílówó.
E jò ó Erànmílówó. Oko tí ó fémi sílé láti odún mérin séyìn, máa ń fowósí fóòmú rè wípé òun kò tí ní ìyàwó nígbà kúgbà tí ó bá ye kí ó so pé òhun ti láya. Yàtò sí ìyen ...
Read More »Ìdí Tí Ó Fà Á Tí Mi Ò Ní Fi Lo Káàdì Ìrántí (Memory Card) Láyémi Mó.
Ìdí méji pàtàkì tí mi ò fi lo káàdì ìrántí (SD card) mó. SD card tí a mò sí káàdì ìrántí (memory card) tí a tún mò sí káàdì ìrántí ìtá “external memory “,ní tòótó ó jé ohun tí ó ...
Read More »Okò Ńlá Tí Ó Kérù Ta Òkìtì Ní Òpópónà Ojúelégbà Ní Ìlú Èkó Látàrí Àìmu Bírèkì.
Lagos response unit LRU tí a mò sí ìgbìmò ìdálóhùn wá ònà láti gbé okò ńlá tí ó kó yoyo tí ó ta òkìtì látàrí àìmu bírèkì ní òpópónà ojúelégbà, lónà pápá bóòsì dúró (Stadium bus/stop) kúrò. LRU gbé okò ...
Read More »