OBALUAYE!!!!!! OOOOOOO cc- Babalawo Ifakayode Oyedele Osaifa
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Oniwowo ado! Baba dakun ma na mi o! Aase!
OBALUAYE!!!!!! OOOOOOO cc- Babalawo Ifakayode Oyedele Osaifa
Read More »ayangalu Comments Off on Foto ode’oni – 13.07.2016
Saheed osupa akorede ati baba wande.
Read More »Edakun kini oruko olorin yii
Read More »ayangalu Comments Off on Gbogbo wa ni o bo ikin la! Aase!
IFA NI Asese roko agbe adabi akiti ohun obo Adifafun Ajala yobo Ikin la lese oke ebo won ni kose ogbebo ni be osebo bi kasai bokinla olowo Ajala bi kasai bo Ikinla emin ateyin ololufemi gbogbo wa labo ikin ...
Read More »ayangalu Comments Off on Awo Ori – Odu Odi Meji
Odidi kirimu kirimu, Awo Ori A difa fun Ori Ori n be logbere oun nikan Ebo won ni kowa se O gbebo nibe O rubo Kerekere Oju wa, Eti wa, Imu wa, Enu wa Gbogbo won wa ba Ori duro ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ogulutu Oro Toni – 09.07.2016
Hummmmmmmm igbiyanju lagbe ngba Olohun lomu isu ta #woo_orewa Nje o mo pe eni tio sun(sleep) lo nsun(move)????? ??? Gbiyanju lati tesiwaju loni majeki ijakule re fao seyin nigbesi aiye re #gbomi_dada Koseni tio ni #sugbon tie gboju re kuro ...
Read More »ayangalu Comments Off on Akara Imora’n toni – 09.07.2016
*Emi ko ni ku saaju ojo ayo mi.*Emi ko ni fi ewon logba.*Iji aye ko ni gbe mi lo(Ase Edumare). …………. #AKARA_IMORAN : Gbiyanju lati ni iwe iranti fun awon olooore re; ki o si gbiyanju lati fa iwe asise ...
Read More »Oro buruku pelerin erin’kkkkkk Mo sese ri eran ewure ni ibi to pokunso so ni in Eran ti moni ki a fe se odun lo pokunso yi ooo Mi o mon nkan to nba leru o erin’kkkkkk
Read More »Bi oro aye se ri ni yen oooo Bi poopo sin-sin odun se wa nta. Olodumare ti se bi o se nse fun awon ebi iya wa Bukky Ajayi Iya ti lo ni aro yi o. Gbogbo eyin Omo Ooduarere o ...
Read More »ayangalu Comments Off on Tani Onife Si Julo Ninu Awon Osere Meji Yi ?
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more