Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC À fi kí á bẹ Ọlọ́run kó bá wa dásí ọ̀rọ̀ àjàkálẹ̀ àrùn ajániláyà pàtì yìí, bí àwọn tó ní kòrónáfairọ̀ọ̀sì ní Nàìjíríà ti ń peléke ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
ayangalu Comments Off on Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC
Èsì àyẹ̀wò tuntun Nàìjíríà fihàn pé “313” èèyàn ti gbàlejò Kofi 19 …àjọ NCDC À fi kí á bẹ Ọlọ́run kó bá wa dásí ọ̀rọ̀ àjàkálẹ̀ àrùn ajániláyà pàtì yìí, bí àwọn tó ní kòrónáfairọ̀ọ̀sì ní Nàìjíríà ti ń peléke ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ààrẹ Buhari dijú lé Ọ̀gá Àjọ NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn tó jàjẹbánu
Ààrẹ Buhari dijú lé Ọ̀gá Àjọ NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn tó jàjẹbánu Ààrẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Muhammadu Buhari ti fi ọwọ́ òṣì júwe ilé fún adarí àjọ elétò ìdánwò àṣekágbá ti girama, NECO àti àwọn mẹ́rin mìíràn lórí ẹ̀sùn pé ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀
Ọ̀daràn kan fi tipá wọ ààfin Ọ̀ọni ilé ifẹ̀ A kìí gbélé ẹni ká fi ọrùn rọ́ ni a ti ń gbọ́ tipẹ́ tipẹ́, sùgbọ́n kín wá ni ká ti pe tirúfẹ́ ìṣẹ̀lẹ̀ ajániláyà yìí tó wáyé ní ààfin Ọọ̀nirìṣà ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ọmọọsẹ́ tó súnmọ́ mi jù lọ satọ́nà bí wọ́n se jí ìbejì mi gbé — Akewugbagold
Ọmọọsẹ́ tó súnmọ́ mi jù lọ satọ́nà bí wọ́n se jí ìbejì mi gbé — Akewugbagold Ṣé wọ́n ní olè kò ní jàgbà, kó má kó fìrí, bẹ́ẹ̀ bíkú ilé ò pani,yóó sòro díẹ̀ kí kú tòde pààyàn . Ọ̀rọ̀ ...
Read More »ayangalu Comments Off on Èèyàn ẹgbẹ̀rún kan àti irínwó dín mẹ́fà bá Kofi 19 rìn l’Amẹ́ríkà lópin ọ̀sẹ̀.
Èèyàn ẹgbẹ̀rún kan àti irínwó dín mẹ́fà bá Kofi 19 rìn l’Amẹ́ríkà lópin ọ̀sẹ̀. À fi kí á bẹ Ọlọ́run kó báwa dáwọ́ ibi dúró nílẹ̀ yìí àti lókèèrè to rí igbi gbogbo la lẹ́ni sí lórílẹ̀.Gbogbo ìgbà ni àjàkálẹ̀ ...
Read More »ayangalu Comments Off on Iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ti ṣe àfihàn àwọn afurasí tó jí ìbejì Akeugbagold gbé ní ìlú Ìbàdàn
Iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ti ṣe àfihàn àwọn afurasí tó jí ìbejì Akeugbagold gbé ní ìlú Ìbàdàn Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, àṣẹgbé kan kò sí, àsepamọ́ ló wà.Ni báyìí, kélé òfin ti mú àwọn ọ̀daràn tó jí àwọn ìbejì Alhaji Taofẹẹq ...
Read More »ayangalu Comments Off on Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn covid-19
Raymond Dokpesi sé̩gun àrùn coronae̩i Aja to rele Ekun to bo, o ye ki a kii ku ewu.Gbajugbaju oludasile ileese redio ati telifison Ray power ati AIT ni o se alabapade ajakale arun coronavirus ni nnkan bii ose meji to ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ìjọba àpapọ̀: À nì sẹ́, dan dan l’óúnjẹ ọfẹ fún ọmọ rẹ, kíláàsì kínní dé ìkẹta alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀
À nì sẹ́, dan dan l’óúnjẹ ọfẹ fún ọmọ rẹ ,kíláàsì kínní dé ìkẹta alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀- Ìjọba àpapọ̀ Iléeṣẹ́ tó wà fún ìpèsè ohun ìrànwọ́ nílẹ̀ wa ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yìí nínú àtẹjáde kan tó fisíta lójú òpó abẹ́yefò Twitter ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ó dìgbà Kehinde Ayoola, Makinde, PDP, APC, ALGON ,ṣe ìdárò akọni
Ó dìgbà Kehinde Ayoola, Makinde, PDP, APC, ALGON ,ṣe ìdárò akọni Bá a kú làá dère, èèyàn kò sunwọ̀n láàyè.Gómìnà Ṣèyí Mákindé ti sàpèjúwe ọ̀kan lára àwọn Kọmíṣọ́nnà rẹ̀, Kẹhinde Ayọọla tó papòdà ní Ọjọ́bọ, ọjọ́ kẹrìnlá oṣù karùn ún ...
Read More »ayangalu Comments Off on Ewì Toni: Ìwà rere
*Ìwà rere*Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà’bàjé ní jẹ́ k’ọ́mọ o j’ìyàẸwúrẹ́ ya aláìgborànÀgùntàn jẹ́ oníwàpẹ̀lẹ́Adígbánnákú ṣẹ̀yìn gákangàkan Iléere ní ẹ̀ṣọ́ nínúÌwà rere lẹ̀sọ́ ènìyànÌwà rere ni òbí ní,tí wọ́n fi ń ǹpé ní òbí rereÒbí rere ló le kọ́mọ ní’wà rereÒbí ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more