Awon osise ajo olomi ti ipinle Kwara tu jade lojo Isegun to koja yii niluu Ilorin nigba ti won fi ehonu won han nipa owo osu won eleyii ti ijoba ipinle naa ko lati san lati inu osu keje seyin. ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on Niluu Ilorin: “Awon osise mefa ti ku, awon kan wa nile iwosan”- Akowe egbe osise
Awon osise ajo olomi ti ipinle Kwara tu jade lojo Isegun to koja yii niluu Ilorin nigba ti won fi ehonu won han nipa owo osu won eleyii ti ijoba ipinle naa ko lati san lati inu osu keje seyin. ...
Read More »admin Comments Off on Won o je ki Saraki o rona gba leyin to fun awon minisita Buhari lona lo
Olayemi Olatilewa Ile ejo kotemilorun to kale siluu Abuja ti da esun aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki nu patapata. Ninu esun ti Saraki gbe lo si ile ejo, ibe ni Saraki ti n ro ile ejo lati pase ...
Read More »admin Comments Off on “Eyin ni agbara ati isegun mi l’Ojoosegun”: Ipinle Oyo gba leta Ajimobi
Olayemi Olatilewa Gomina ipinle Oyo, Abiola Ajimobi ti gbe sadankata fun awon eniyan ipinle Oyo fun atileyin ti won se fun un lati segun niwaju ile ejo to n risi awuyewuye eto idibo to waye lojo isegun to koja yii. ...
Read More »admin Comments Off on Won Fadi Omo Odun Meji Ya Niluu Abuja
Olayemi Olatilewa Omokunrin eni odun merindinlogun (16) kan ti lo foju ba ile ejo niluu Abuja leyin asemase pelu omobirin, eni odun meji (2) kan. Iroyin yii lo jade nigba ti olupejo, ogbeni Adama Musa, eni ti n soju ile ...
Read More »admin Comments Off on Owo te awon omo egbe okunkun niluu Ado-Ekiti
Olayemi Olatilewa Awon akekoo meji ile iwe gbogbonise ti ijoba apapo (Federal Polytechnic) to kale si Ado-Ekiti ati maanu kan ti n tu foonu se ni agbegbe naa ni won ti ko lo si iwaju ile ejo Majisireeti pelu esun ...
Read More »admin Comments Off on Ireti Odegbami ja sofo lati di aare FIFA agbaye
OlayemiOlatilewa Bi o tile je wi pe ajo ere boolu ile Naijiria ti n fenu so wi pe gbagbaagba ni awon wa leyin agbaboolu to gba boolu metalelogun (23) sawon ni akoko ti n gba boolu fun orileede Naijiria, ...
Read More »admin Comments Off on “Bilionu lona bilionu owo naira ni Mimiko dabaru ni ipinle Ondo” – Alagba egbe APC
Olayemi Olatilewa Alaga egbe oselu APC eka ti ipinle Ondo, ogbeni Isaac Kekemeke ti fesun kan Gomina Olusegun Mimiko to je omo egbe oselu PDP nipa wi pe owo bi tirilionu kan naira (N1 trillion) ni gomina ti je mole ...
Read More »admin Comments Off on Ile ise Ologun seleri owo tabua fun eni to ba ri Boko Haram
Olayemi Olatilewa Ile ise Ologun ile Naijiria ti se afihan foto awon ogbologbo alakatakiti esin Islam, Boko Haram bi ogorun (100) eleyii ti won on wa lati mu. Awon wonyii ni won se apejuwe won gege oloye agba ti ...
Read More »Lolade Comments Off on Foto Mercy Aigbe meje (7) to ta lenu bi ataare
Ti ija ba wa ni be, e je a pari kia. Awon Yoruba si bo won ni tomo eni ba daa kawi, kii se ka fi saya. Egan ni he, Mercy Aigbe ta lenu bee lodun yungbayungba. Olayemi ti mo ...
Read More »Lolade Comments Off on Awada Kerikeri: Awon ole meji ti won lo fo banki
Awon ole meji ja ilekun banki kan loru ojo kan, won si n si awon seefu wo. Ninu akoko, yugooti bi i meloo kan ni won ri nibo, kò s’ówó. Won to yugooti naa wo, o ti kan lenu. Won ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more