Home / Art / Àṣà Oòduà (page 163)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Ewo lo lagbara ju ninu gbolohun wonyi lagbo ife ?

Moki gbogbo ile, e gbo ewo lo lagbara ju ninu gbolohun wonyi lagbo ife ? 1, o ti pari laarin emin ati iwo 2,odabo 3, min o ni ife re 4, mo ti un fe elomiran 5, ma pe ero ...

Read More »

E fura ooo!!

Eyi ni lati sofun yin wipe anwa arakunrin kan ti oruko re nje Mukaila,ti o je onisowo eran maalu ni onibuore ni agbegbe iyana church ni ilu Ibadan. Arakunrin yi ni awon kan pe lati ori ero ilewo re lati ...

Read More »

Oruko Kan fun Arakunrin ?

Read More »

Otura alaketu/ Otura mele/ Otura owonrin !

1.Tooro toki Adifafun Alamala ketu,ekun ire lo n sun won ni ebo ni ko se,iya o si baba o si tooro toki ope gbigba ni o gba mi tooro toki. 2. Ewe le ole le alele le wure adifafun Orunmila ...

Read More »

Iru Eranko Wo Leyi?

Read More »

Ifa orimi reooo !

Read More »

Ejowo eba mi wa Oruko kan fun omode yii .

Read More »

Omo Yooba toba dibo fun Jonata omo ale ni -Sen. Anthony

Read More »

Se iru ife bayi tun wa?

E ba mi dasi eto yii E dakun Se iru ife bayi tun wa??

Read More »

Ta le Feran ju ?

FUNSHO ADEOLU tabi YOMI FASH LANSO

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb