Ìpẹpẹrẹ ìmọ ni farabalẹ ni jogunda Adia fun Orunmila Ifa nlọ ba wọn mulẹ budo Nita Iku nita Arun, Nita Ajogun Mẹrẹrindilogun Te nbẹ lode oṣalaiye. Slender-Palm-Frond-is-Patient-In-Taking-Its-Revenge Revealed the way to Orunmila when he was looking for a place to ...
Read More »Ará Ọ̀run
Cc – Moyo Okediji
Read More »Ifa naa ki bayi wipe…
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin ku isimi opin ose, eledumare yio saanu wa o ao ri tiwa se loni, iyan jija koni ranwa lo sibiti ako fe o ase. Odu ifa ogbeweyin ni ...
Read More »Odo Iwoyi: Oro Kan Ni Nrumi Loju Ti Mo Si Nilo Amoran Lori Re.
E ku ile ni a n k’ara ile, e ku abo ni a n k’ero ona, ti a ba ti rira eni tipe, e ku atijo ni a ma nki ara eni. Mo ki gbogbo ebi Omo Yoruba Atata pata ...
Read More »Ifa Toni Ki Bayi Wipe
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, oni a san wa o, eledumare yio gbo ohun ebe adura wa o ase. Ifa toni ki bayi wipe: Orunmila ni ori a lana kan Moni ori a lana kan ...
Read More »Oju-Abe: Aare Mohammodu Buhari pase fun oga Agba Olopaa
Aare ile wa Nigeria, #Aare_Mohammodu_Buhari ti pase fun oga Agba yan-an-yan fun awon Olopaa nile wa lati tenu bo iwadii lori awon Ajo tiwon da sile lati maa pese Ounje ati Ohun-eelo fun awon Eeyan ti Iko-Onilakaadi-Ajajangbila #BOKOHARAM tiso di ...
Read More »Omo Oodua Rere Nkan Semi Ose Idile Mi Pelu Nkan…
Omo oodua rere nkan semi ose idile mi pelu nkan lani ki majesi o ti oju obie re orun ara ma bo egbon mi jade laye ni ijeta ojo kinni osu kesan loju iyawa ha ha ha o ma se o ...
Read More »Kini itumo asanya oro yi
Kilo ri lobe??? (A) TOFI GAARU OWO. (B) TOFI WARU SOWO.
Read More »Today’s Sermon – (Ijo Orunmila Ato) inc, Taken From Ejiogbe
My sermon today, Sat.3rd Sept. 2016 at our House of Worship, Indigene Faith of Africa( Ijo Orunmila Ato)Inc, taken from Ejiogbe:- Akole/ Theme Iwa onikaluku la o fi da l’ejo By their characters shall they be judged Isepe werewere ...
Read More »Olojo Ibi Toni -04.09.2016
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alagba Daud Adewuyi ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ...
Read More »