Nje e le biliifu eleyii? Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa. Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won. Awon ore iyawo meji to tele won, ibeji ni won. Awon omo iyawo obirin, ibeji ...
Read More »
Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.
admin Comments Off on E wo ohun ti won fi ibeji da lara
Nje e le biliifu eleyii? Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa. Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won. Awon ore iyawo meji to tele won, ibeji ni won. Awon omo iyawo obirin, ibeji ...
Read More »admin Comments Off on Inu fiimu wo ni aworan yii ti jade?
admin Comments Off on Yeepa! Mercy Aigbe di Sulia Ayetoro
Sulia kan, Mercy kan, Walahai Ayetoro kan ni
Read More »admin Comments Off on Arun oju: Ohun ti e o se ti oju ba n su tabi yun yin
Ti oju ba yun eniyan, tabi ti oju naa ba n su. Olayemi Oniroyin ti lo sewadii nipa ona ti eniyan fi le setoju iru oju bee lona to rorun ju lo. Ti eni naa yoo si bo ninu wahala ...
Read More »admin Comments Off on “Eyan Mayweather” ni awo orin tuntun Olamide Ogbeni (Mr) . Baddo
Olamide, Ogbeni (Mr) Baddo ti kede ojo ti yo ju awo orin re tuntun sigboro aye. Awo orin tuntun to pe akole re ni “Eyan Mayweather” ni yoo maa dagboro ru, bere lati ojo ketalelogun osu kokanla odun yii (23/11/15). ...
Read More »admin Comments Off on Mercy Aigbe alaso oge pade Toke Makinwa
Awon Yoruba bo, won ni tode-tode ni i se alaso tuntun. Joojumo ni Mercy n sodun, Mercy Aigbe alaso oge. Mercy tun pade Toke, sorosoro ori redio ati telifisan ti oun naa feran oge lagbo ariya.
Read More »Kosi eni ti Olorun ko le fi owo to lokan. Maheeda, okan ninu awon olorin ile Naijiria, ti ma n bora sile nihoho tele ti wa di eni ti n gba awon eniyan niyanju bayii pelu oro itunnu ti n ...
Read More »admin Comments Off on Dayo Amusa ti pada senu ise
Dayo Amusa wa lara awon ero Mecca odun yii pelu awon akegbe re bi Fathia Balogun ni won jo goke arafa papo. Igba ti won de ni won di Alaaja tuntun. Sugbon bayii, Dayo ti pade sidi ise oojo re nibi ...
Read More »admin Comments Off on Donald Duke se afihan iwa omoluabi ati irele
admin Comments Off on Eleleture lati owo Akeem Lasisi
Eyi ni fidio orin ewi lati owo Akeem Lasisi ti won pe akole re ni ELELETURE
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more