Banky W lórí ìkúnlè ní iwájú awon emèwà rè nígbà tí won ro òjò àdúrà fun.Àwòrán rí ó rewà níbi tí àwon egbé oko (Banky W) ti n se àdúrá fún òré won tí ó n lo sí ìgbé ayé ...
Read More »
Banky W lórí ìkúnlè ní iwájú awon emèwà rè nígbà tí won ro òjò àdúrà fun.Àwòrán rí ó rewà níbi tí àwon egbé oko (Banky W) ti n se àdúrá fún òré won tí ó n lo sí ìgbé ayé ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Musiliu Obanikoro ti fi tòwòtòwò darapò mó egbé APC.
Olóyè Musiliu Obanikoro ti fi tòwòtòwò fi egbé alásìá, PDP (People Democratic Party)sílè lo dí egbé onígbálè APC (All Progressive Congress). Ìròyìn jé kí á mò wípé ìgbésè Obanikoro lo sí egbé tuntun ti bèrè láti bi osù mélòó séyìn ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Ebuka Obi-Uchenda àti ìyàwó rè, Cynthia Obianodo níbi ayeye ìgbéyàwó alárédè ti Banky W àti Adesua Etomi.
Ojó tí a ti n retí ti pé o! Ebuka pín àwòrán aso tí wò lo sí #BAAD2017 tí ó túmò sí Banky Adesua 2017. Níbi tí ó ti fi ara rè hàn. E wo bí gbajúgbajà yí ...
Read More »chucks Comments Off on Maggi Anwuli Oputa: Nwa nwanyi nwa nwoke Charly onye bu Onye newulite anu aru ma burukwa nne nke umu asaa.
Maggy Anwuli Oputa bu nne nke umu asaa mana anuaru ya adokachala, O bu onye newulite anuaru. Nna ya Charly Nwoke, Onye bu nna Ogbe, Kere foto Maggy na asomumpi nke ndi newulite anuaru we dee Ihe a: Adaeze ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Arábìnrin tí ó n gba ààwè funfun fún Wizkid láti ségun àwon òtá rè.
Odóbìnrin kan ní orílè èdè Nàíjíríà, Bosslady ni orúko rè n jé ní orí èro ayélujára (Instagram) ti jé kí ó di mímò wípé òun n gba ààwè funfun fún Wizkid, nítorí bí ó se so ó ní Wizkid ní ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Èmi ni mo ko àkosílè orin tí Davido sèsè ko tí ó n jé “like that” Teni tí ó jé adá ni lára yá , Teniola Apata.
Olórin kan ní orílè èdè Nàìjíríà adá ni lára yá Teni ti pin sí orí èro ayárabíàsá (Twitter) láti fi hàn wípé òun ni òun ko àkosílè Orin tí gbajúgbajà olórin Davido sèsè ko, ó ní òun ni òun ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Jude Okoye tí ó jé ègbón àwon psquare ti rò wípé àsìkò ti tó kí òun sòrò lórí Aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè.
Ó ti dá àwon olólùfé won lóhùn lórí èro ayélujára (Instagram), Jude Okoye ti fi ogbón sòrò nípa aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè tí ó sí wípé òun kó ni olórí ebí won. Ó ko síbè wípé. ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Okò tí ó gbé epo petiírólù àti okò èrò ni ó kolu ara won ní Orlu Imo, ogbòn èèyàn ni ó kú.
Ìjàmbá nlá ni ó selè ní orí afárá (bridge) tí ó gbajúgbajà ní Njaba lónà Umuaka – Okwudor ní ìpínlè Imo. Gégé bí ìròyìn se so okò epo petiírólù àti ti gáàsì tí ó kolu bóòsì elérò méjìdínlógún ní Orlu, ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Odóbìnrin àgùnbánirò tí ó jé omo odún mérìnlélógún (24), ni won sin ní ìpínlè River.
Ojó díè séyìn ni won pín ìròyìn burúkú tí ó selè sí omo odún mérìnlélógún yí tí ó jé àgùnbánirò, tí a mò sí Miss Chinda Uchechi Happiness, ni ó pàdánù èmí rè ní ojó kokàndílógún osù kokànlá (November 19) ...
Read More »Awoyemi Bamimore Comments Off on Maryam Sanda ti sun ekún àsun-n-dáké nígbà tí won gbe lo sí ilé-ejó látàrí ikú tí ó se pa oko rè Billyaminu Bello.
Maryam Sanda tí won fi èsùn kàn wípé ó gún oko rè Bilyaminu Bello tí ó jé omo alága egbé PDP télè, Haliru Bello pa ní ilé won ní Abuja ní ojó àìkú (Sunday) tí ó kojá, ni ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more