E bami kaa si eti awon omo ni ile, January – seere February- Irele March – Erena April – Igbe May – Ebibi June -Okudu July – Agemo August – Ogun September -Owewe October – Owawa November – Beelu December -Ope.
Read More »Aderupoko lori Eto Gbajumo Osere
Bobo B lori Eto Gbajumo Osere
YORÙBÁ DÙÚN KÀÁÁÁ
A – Alaafia ni fun o. B – Buburu kan ki yo o subu lu o. D – Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l’ori. E – Ebi o ni pa o nibi ti odun yi ku si. E ...
Read More »Olojo Ibi
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa TUNRAYO IBRAHIM ti won je okan pataki ninu ebi Oodua Rere. Iyalode olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ...
Read More »Talo ma pani lerin julo ninu awon won yi?
Ebeere Toni: Talo ma pani lerin julo ninu awon won yi?
Read More »Iwure Owuro Toni: 24-04-2016
E MAA WI TELE MI : …… *Ade ogo mi ko ni si danu. *Aso iyi, aso eye mi ko fa ya. *Edumare ma je ki n fi ota se ore. *Oluwa dakun so egan mi dogo. *Edumare wa so ...
Read More »Ojuitere ooooooo!!
mo de werewere bi eji-ale mo de warawara bi ti iyaleta, ewe-itu lo ni ke tu mise ewe-iifa loni kefa mi mora, toripe enikan ki so okun mo igbin lorun, won ki fi pakute mu eja l’odo, beni omode koni ...
Read More »Eyin tia, e ku isinmi oni!
ARAYE KONI LU FUN WA JO, BATA-OFO, BATA- IBANUJE BATA-WAHALA won o ni bo si enu- onan gbogbo wa, gbogbo eniyan tiko ba yan Eledua l’odi e bami se ase, toripe INU- ALAGBAFO KI LE TITI KO BINU OMI. oju-itere ...
Read More »Ori Apere
Atete gbeni ju Orisa Ori atete niran Ori lokun Ori nide Ko si Orisa ti dani gbe leyin Ori eni Ori ni seni ta a fi dade owo Ori ni seni ta a fi tepa ileke woja Ori gbe mi ...
Read More »