Awon omo egbe oselu APC eka ti ipinle Ondo ti bu enu-ate lu Gomina Olusegun Mimiko ti awon kan tun pe ni Iroko gege bi asaaju ti ko mo eyi to kan lati muse. Atejade yii lo jade nigba ti ...
Read More »
admin Comments Off on “Ayojuran ni Mimiko lo se niluu Bayelsa”- Egbe APC
Awon omo egbe oselu APC eka ti ipinle Ondo ti bu enu-ate lu Gomina Olusegun Mimiko ti awon kan tun pe ni Iroko gege bi asaaju ti ko mo eyi to kan lati muse. Atejade yii lo jade nigba ti ...
Read More »admin Comments Off on Laasigbo to be laaarin Olubadan ati Gomina Ajimobi
Awon agba ti yanju laasigbo to be sile laaarin Olubadan ati Gomina Ajimobi *Wahala naa sele leyin ti Olubadan fi Ladoja je Osi Olubadan Gomina Abiola Ajimobi Ikunsinu lo bere laaarin Olubadan tile Ibadan, Oba Samuel Odulana Odugade ati gomina ...
Read More »admin Comments Off on “Awon irinse ti a n lo ti darugbo”- Oga panapana ilu Eko
Oga agba ileese panapana ti ijoba apapo, Federal Fire Service, eka ti ipinle Eko, Ogbeni Aderemi Olusola Theophilus ti sapejuwe ikiyesara gege bi ogun-ajisa lati dena ijamba ina abaadi. Ninu oro re, eleyii to so lori telifisan ipinle Eko, o ...
Read More »admin Comments Off on Aye awon asewo nile awon omo yahoo-yahoo
Bi yahoo-yahoo ni won ni abi ogun oloro ni won gbe, ta lo mo. Sugbon o daju wi pe, eni to n sise gege bi omoluabi ko ni da iru eleyii lasa wo laelae. Ori ayelujara ni aworan yii ti bere ...
Read More »admin Comments Off on Obirin kan bi omo sinu Keke Maruwa
Onise ara ni Olorun oba. Omobirin alaboyun kan lo bere si ni robi ninu Keke Maruwa ni akoko ti won gbe lo si ile iwosan lati lo bimo niluu Enugun. Eyi to ju ibe ni wi pe, ojo odun lo ...
Read More »admin Comments Off on Won ti fi Ladoja je Osi Olubadan
Won ti fi Senator Rashidi Adewolu Ladoja je Osi Olubadan lonii (01/01/16) ni aafin Oba Samuel Odulana Odugade, Olubadan tile Ibadan.
Read More »admin Comments Off on Amosun se ileri ipe ofe ori foonu fun awon osise lodun 2016
Ijoba ipinle Ogun, labe akoso Senator Ibikunle Amosun, ti se ileri ipe ori foonu ofe fun gbogbo awon osise ipinle naa lodun tuntun 2016 to wole de yii. Igbese tuntun yii ni olori eka imo ero ati ibanisoro, Ogbeni Olatundun ...
Read More »admin Comments Off on Davido ti toro aforijin lowo Dele Momodu
Davido ti toro aforijin lowo Dele Momodu fun awon oro alufansa to so si i lori wahala to wa laaarin re ati afesona re igba kan, Sophie Momodu to je aburo Dele Momodu,
Read More »admin Comments Off on E pade awon ore yin nibi
Orisiirisii ona ati idi pataki ni awon eniyan fi n yan ore tuntun. Awon kan fe alajoso, awon kan fe alabaro, awon kan si n fe eni ti won yoo jo maa takuroso lasan. Eyiowu ko je, ore dun ti ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more