Home / Art (page 230)

Art

redeem

Won gun pasito ijo RCCG lobe niluu Ota

Edward Campbell, eni odun mokandinlaadota (49) ni won ti gbe lo si ile ejo lojo Eti to koja yii pelu esun wi pe o gun pasito Redeemed Christian Church of God (RCCG), Dotun Olojede, lo be. Ile ejo Majisireeti to ...

Read More »
malu

Ijamba buruku kan lo waye loju ona masose Ilesa si Ibadan

Awon Yoruba bo, won ni iku ti o ba pani, toba si fila eni lo ope ni ka maa du. Ijamba buruku kan lo waye loju ona masose Ilesa si Ibadan l’Ojobo ose to koja yii nigba ti maalu awon ...

Read More »
Simisola Omoayan

Simisola Omoayan: Omidan ti n filu dara

O ti wa daju wi pe kosi oun ti okunrin se ti obirin o le se. Bi eniyan ba si foju kere ata, afaimo ki iru eni bee ma kabamo leyin oro. Eni Edua Oke ba fe ni i fun ...

Read More »
Oloye Omowale Kuye

Otun Olubadan tile Ibadan ti dagbere faye

Otun Olubadan ti ile Ibadan, to tun je okan pataki ninu awon agba oye ile Ibadan, Omowale Kuye, ti dagbere faye leni odun metadinlaadorun (87). Oloye yii la gbo wi pe o dake ninu ile re to wa ni agbegbe Ikolaba ...

Read More »
abule

Abule wo ni sisi yii ti wa na?

Eleyii tun gaju!

Read More »

E wo ohun ti won fi ibeji da lara

Nje e le biliifu eleyii? Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa. Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won. Awon ore iyawo meji to tele won, ibeji ni won. Awon omo iyawo obirin, ibeji ...

Read More »

Inu fiimu wo ni aworan yii ti jade?

Read More »
mercy

Yeepa! Mercy Aigbe di Sulia Ayetoro

Sulia kan, Mercy kan, Walahai Ayetoro kan ni

Read More »
arun oju

Arun oju: Ohun ti e o se ti oju ba n su tabi yun yin

Ti oju ba yun eniyan, tabi ti oju naa ba n su. Olayemi Oniroyin ti lo sewadii nipa ona ti eniyan fi le setoju iru oju bee lona to rorun ju lo. Ti eni naa yoo si bo ninu wahala ...

Read More »
olamide

“Eyan Mayweather” ni awo orin tuntun Olamide Ogbeni (Mr) . Baddo

Olamide, Ogbeni (Mr) Baddo ti kede ojo ti yo ju awo orin re tuntun sigboro aye. Awo orin tuntun to pe akole re ni “Eyan Mayweather” ni yoo maa dagboro ru, bere lati ojo ketalelogun osu kokanla odun yii (23/11/15). ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb