Ti eyin ko ba tii ra iwe Iroyin Owuro to jade lose yii, a je wi pe iroyin ku sibi kan te e ti gbo. Lati ori oro oselu de amuludun, awon oro to n lo ati igbelaruge asa ati ...
Read More »
Lolade Comments Off on Iwe Iroyin Owuro ose yii kun fofo bi ataare
Ti eyin ko ba tii ra iwe Iroyin Owuro to jade lose yii, a je wi pe iroyin ku sibi kan te e ti gbo. Lati ori oro oselu de amuludun, awon oro to n lo ati igbelaruge asa ati ...
Read More »Lolade Comments Off on Ahmed (Amedi) Musa lo rawon julo bayii niluu Russia
Ogbontarigi agbaboolu omo Naijiria, Ahmed Musa, ti n le waju bayii ninu awon agbaboolu to rawon julo niluu Russia. Iroyin yii jade ni kete ti egbe agbaboolu re, CSKA Moscow jawe olubori nigba ti won pade pelu Dynamo pelu ayo ...
Read More »Lolade Comments Off on See Top 9 Creative Works Celebrating #NigeriaAt55
54Artistry.com compiled main 55 inventive works from its #Diary55 campaign where imaginative Nigerians uploaded their works on 54artistry.comand/or Instagram to mark Nigeria at 55. See beneath the top 9 creative works from the various sections.
Read More »Owo awon olopaa ilu London ti te Diezani Alison-Madueke to je minisita fun epo robi nigbakan labe isejoba Goodluck Jonathan. Alison-Madueke ati awon merin kan ni owo te laaro ojo Eti to koja yii pelu esun Jegudujera, riba ati sise ...
Read More »Iru sitayi wo leyii?
Read More »Ara opo awon omo Naijiria tun ya gaga si orile ede won lojo Alamisi to koja, nigba ti a se ayeye ominira odun karunlelaadota. Kaakiri awon ipinle, opo eniyan lo ki akegbe won ku oriire, ti won si n soro ...
Read More »admin Comments Off on Awon Oruko Minisita Buhari Lati Enu Awon Omo Naijeria Niyii
Awon Minisita Buhari: Niwon igba ti awon ara ilu si n reti oruko awon eniyan ti Aare Buhari fe fi je minisita, awon oruko wonyii ni awon ara ilu ni oseese ko jeyo ninu awon oruko minisita ti Buhari ko ...
Read More »admin Comments Off on Ajimobi ati Amosun Da Ara Ilu: Won Ni Ko Si Eko Ofe Mo
Lati inu iwe Iroyin Owuro to jade lose to koja ni iroyin naa ti jade wi pe Ajimobi ati Amosun ti pada ninu ileri eto eko ofe ti won se ileri re fun awon ara ilu. Won ni ki olomu ...
Read More »admin Comments Off on Se N’Ibadan Tia Nile Oluyole?
Ibadan tia! Se n’Ibadan tia? Ibo lawa o mo lOluyole Ibadan? MAPO d’AYẸYẸ Gbogbo ODÍNJÓ tia ni, ELEKURỌ, ALEKUSỌ, Ibo gan-an lawa o mo n’Ibadan? BẸRẸ titi to fi de ÒÓPÓ Yoosa, Ibi to ku taa mo ni ke e ...
Read More »admin Comments Off on Tai Solarin Dilu Nla
Tai Solarin dilu nla Tai Solarin ile ẹkọ nla to dilu nla. Ibi ọgbọn gbe pamọ si. Arọni imọ ti n ja ni laya bi oke. Gbékanlùkan isẹ ọpọlọ to fakíki. Kinihun o jẹran ikaṣi. To ba jọ bi irọ, ...
Read More »
Ọmọ Oòduà Naija Gist | News From Nigeria | Entertainment gist Nigeria|Networking|News.. Visit for Nigeria breaking news , Nigerian Movies , Naija music , Jobs In Nigeria , Naija News , Nollywood, Gist and more