Ààrẹ Buhari kí àwọn ọmọ Nàìjíríà kú àfaradà bí gbogbo nǹkan ṣe ń lọ lásìkò Coronavirus yìí Nínú ọ̀rọ̀ ìkínni kú ọdún Àjíǹde tó fi ṣọwọ́ sáwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ààrẹ Buhari ṣàlàyé pé ìgbáyégbádùn àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kìí ...
Read More »Àwọn dókítà ilẹ̀ China tó wá sí Nàìjíríà kò ní tọ́jú aláìsàn kankan’
Àwọn Dókítà láti ilẹ̀ China tó ṣẹ̀sẹ̀ dé sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nítorí àjàkálẹ̀ àrùn Coronavirus kò ní tọ́jú aláìsàn kankan. Iléeṣẹ́ láti ilẹ̀ China to tó ṣe ojú ọ̀nà àti ojú irin( CCECC Nigeria), ló fi àtẹjáde náà léde pé ...
Read More »Ìjo̩ba máa gbé pé̩ré̩gi kaná pè̩lú àwo̩n oníròyìn ìdàlúrú – Lai Mohammed
Minisita fun eto iroyin ati asa ni orileede yii, Alhaji Lai Mohammed ni ijoba apapo ko ni gba ki awon kan fi iroyin aboosi da ilu ru. O ni “oloju ko ni laju re sile ki talubo woo”. O ni ...
Read More »Ẹlẹ́wọ̀n 2600 ni ìjọba tú sílẹ̀ ní Nàìjíríà nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus
Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti tú ẹlẹ́wọ́n tó lé ní ẹgbẹ̀rún méjì sílẹ̀ ní ọgbà ẹ̀wọ̀n káàkiri orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Aregbesọla ní Ìjọba gbé ìgbésẹ̀ náà láti dẹ́kun ìtànkálẹ̀ àrùn Coronavirus ní Nàìjíríà. Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà náà ni àwọn ...
Read More »Òòlù ìdájọ́ ré bá Fúnkẹ́ Akíndélé àti ọkọ rẹ̀ lẹ́yìn, owó ìtánràn, ìgbélé tipátipá, iṣẹ́ ìsìnlú bíi bọ̀kílẹ̀ àfojúdi .
Kò sí n tó burú kí abẹ òfin ba Ògbó Awo tó bá ń se bí ọ̀gbẹ̀rì .Ilé ẹjọ́ ti dá gbajúgbajà òṣèré sinimá, Fúnkẹ́ Akíndélé àti ọkọ rẹ̀ Abdulrasheed Bello lẹ́jọ́ pé ó jẹ̀bi ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn ...
Read More »Àwa kò tíì gba owó ló̩wó̩ e̩niké̩ni – Boss Mustapha
Àwa kò tíì gba owó ló̩wó̩ e̩niké̩ni – Boss Mustapha Ìròyìn láti o̩wó̩ Yìnká Àlàbí Awon igbimo ti ijoba apapo gbe kale lori arun coronavirus ni awon eniyan ti n fi esun inakuna owo kan kaakiri.Eyi lo mu ki olori ...
Read More »Ewi Toni: Egbe APC iba oooo
Egbe ofo Toko coronal wo Nigeria Egbe abamo ti ki tele ofin. Akuse egbe tin pin rice agolo Kan fun eniyan mewa
Read More »Ifa, A Complete Divination By Ayo Salami.
Look for this book: IFA, A COMPLETE DIVINATION by Ayo Salami. It is excellent.
Read More »Oodua Fantasy: Creatures from The Forest of No Return:
Kurekure (Ghomid) observing a (Yinmiyinmi) Dung Beetle Adeboye Adegbenro
Read More »Ṣeyi Makinde, Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Sọ̀rọ̀ Lórí Àrùn Coronavirus Tó Ní
Ìròyìn tó bá ọ̀pọ̀ lẹ́jafùú ni ìròyìn ‘Mo ti ní àrùn Coronavirus’ èyí tí Gómìnà Ṣèyí Mákindé gbé jáde ní ọjọ́ Ajé lójú òpó twitter rẹ̀. Níbáyìí tí ó ti lo ọjọ́ méjì ní ìgbélé lẹ́yìn ìkéde yìí, gómìnà ìpínlẹ̀ ...
Read More »