Home / Art (page 40)

Art

Nipa rogbodiyan ajakale arun coronavirus to n ja kaakiri agbaye to si tun ti rapala wo orileede Naijiria lati bii ose merin seyin. Ijoba ipinle Eko ti ti awon oja ti kii se ti ounje jijie ati mimu. Awon eniyan si n yo ijoba ipinle Eko lenu pe ki o ti gbogbo ilu pa lo le segun arun naa daadaa. Sanwo-Olu da won lohun pe arun naa ko ti ran de iye to le mu ki ijoba ti gbogbo Eko nitori ipo ti ipinle naa wa ni orileede yii. Gomina Sanwo-Olu tun salaye awon to maa letoo si ounje ofe. O ni awon ti eya ara pe nija ati awon arugbo ni eto naa koko wa fun bayii. O ni bi agbara ba se n de sii ni o maa so bi awon se maa te siwaju nipa iranlowo naa. Bayii eniyan aadorin (70) lo ti ko arun buruku naa ti merinlelogoji (44) si sele ni ipinle Eko. Ki Eledua ba wa segun ajakale arun naa.

Sanwo-olu Máa Fún Ẹgbẹ̀rún Lọ́nà Igba Ènìyàn Lóúnjẹ L’eko

Nipa rogbodiyan ajakale arun coronavirus to n ja kaakiri agbaye to si tun ti rapala wo orileede Naijiria lati bii ose merin seyin. Ijoba ipinle Eko ti ti awon oja ti kii se ti ounje jijie ati mimu. Awon eniyan ...

Read More »
Ariwo kí ló ń ṣẹlẹ̀ ní Akure ní àwọn ènìyàn fi bọnu!

Ariwo kí ló ń ṣẹlẹ̀ ní Akure ní àwọn ènìyàn fi bọnu!

Ó kéré tán Ilé méjì tí àwọn ènìyàn ń gbé, ilé ẹkọ ati Ilé ìjọsìn ló wó ní ìlú Akure lẹ́yìn tí ìbúgbàmù dún ní ìpínlẹ̀ Ondo.

Read More »
Ighalo

Manchester United Ti Se Tán Láti Ra Odion Ighalo Pátápátá

Manchester united ti se tán láti ra Odion Ighalo pátápátá Lati owo Akinwale Taophic Se won ni ti egungun eni ba jo re, ori a ma ya atokun re. Ati wi pe, Ku ise ni n mu ori eni ya! ...

Read More »

Ronaldinho Ń Kó̩ Is̩é̩ Gbé̩nàgbe̩nà Nínú È̩wò̩n Ní Orílèèdè Paraguay

Ogbontarigi ninu boolu alafesegba to je omo bibi orileede Brazil ti o si ti fi igbakan ri je eni akoko ninu boolu alafesegba kaakiri agbaye, Ronaldinho,

Read More »
fg

Àfàìmọ̀ Kí Coronavirus Má Dà Bí I Ti China Tabi Italy- Mínísítà Kìlọ̀

Ẹni mẹ́rin mì ìn kó àrùn apinni ní mímí èèmii coronavirus ní Nàìjíríà,àfàmọ̀ kò mọ́ dà bí i ti China,l Italy— Mínísítà kìlọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Ìgbọrọ̀ sàn ju ẹbọ rúrú fún ẹni tó bá fẹ́ gbọ́ ni o.Ó ti di ...

Read More »
Atiku

E̩ Fi Àdúrà Rànmí Lọ́wọ́, Nítorí Ọmọkùnrin Mi Ti Lùgbàdi Àrùn Coronavirus … Igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀ Yìí Nígbà Kan

Ẹ fi àdúrà rànmí lọ́wọ́, nítorí ọmọkùnrin mi ti lùgbàdi àrùn coronavirus … igbákejì Ààrẹ Orílẹ̀ yìí nígbà kan

Read More »
Àwọn Fíìmù Òde Òní Ń Kọ́mọ Lólè Àti Ọ̀pọ̀ Ìwà Burúkú – Iyabo Ogunsola

Àwọn Fíìmù Òde Òní Ń Kọ́mọ Lólè Àti Ọ̀pọ̀ Ìwà Burúkú – Iyabo Ogunsola

Àwọn fíìmù òde òní ń kọ́mọ lólè àti ọ̀pọ̀ ìwà burúkú Fẹ́mi AkínṣọláṢé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní ẹgbẹ́ burúkú ba ìwà rere jẹ́. Ajíyìnrere Felicia Iyabode Ogunsola tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Efúnsetán Aníwúrà, Ìyálọ́de ìlú Ìbàdàn nínú eré, ...

Read More »
corona virus

Ènìyàn O̩gbò̩n Ti Lùgbàdì Coronavirus Ni Naijiria

Ènìyàn o̩gbò̩n ti lùgbàdì coronavirus ni NaijiriaÌròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí Afi ki Eledua maa ko wa yo ni orileede yii. Bi ere bi awada, ajakale arun kogboogun (covid-19) ti mu eniyan ogbon di asiko ti a n ko iroyin ...

Read More »
Peter Fatomilola

Peter Fatomilola ní àìsí ẹ̀kọ́ ń mú káwọn òṣèré tíátà ó máá ṣe oun tí kò tọ́

Ṣé Yorùbá bọ̀ wọ́n ní báyé bá tojú àgbà bàjẹ́, àìmọ̀wàáhù wọn ní. Èyí ló díá fún bí àwọn tọ́rọ̀ kàn lágboolé òṣèré e tíátà se ń lọgun tantan pé,láyé ọjọ́sí, eré ìtàgé jẹ́ gbajúgbajà láwùjọ àwọn onítíátà lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. ...

Read More »

Ọ̀nà Jìbìtì 2

Ọ̀nà Jìbìtì 2Awon miiran maa n duro si opopona bi eni ti moto won baje. Won le mu omo ileewe kan tabi meji si egbe won gege bi eni to nilo iranlowo. Awon to ba duro ti won ti ko ...

Read More »

Viral Video

Support Ooduarere

SUPPORT OODUARERE
Scan QR code below to Donate Bitcoin to Ooduarere
Bitcoin address:
1FN2hvx5tGG7PisyzzDoypdX37TeWa9uwb